Ìdojúkọ Àwọn Akínkanjú Jagunjagun Ilẹ̀ Adúláwọ̀ Lọ́wọ́ Àwọn Ọmọ-Ogun Wọn: Lísàbí Agbòǹgbò-Àkàlà láti Owọ́ Olú Owólabí Gẹ́gẹ́ Bí Àpẹrẹ

O Confronto dos Bravos Guerreiros Negros às Mãos de Seus Soldados: O Estupro das Ambongbo-Akala por Olu Owolabi como Exemplo

Autores

Palavras-chave:

Ilẹ̀ Áfíríkà, Ìjẹgàba, Akínkanjú Jagunjagun, Ìjàjàgbara, Ìdìtẹ̀mọ́ní

Resumo

Ogun kò rí bí iyán, bẹ́ẹ̀ ni ogun kò rí bíi ká sùn ti obìnrin ẹni tó peni lóorun. Ìtàn ṣàfihàn rẹ̀ lónírúurú nípa ìṣekúpani, ìmúnilẹ́rú, ati ìjẹgabá tó máa ń wáyé látọwọ́ àwọn ajunilọ lórí àwọn ìlú tí agbára wọn kò tó nǹkan látara ìgbéraga tàbí ìlara ọmọnìkejì lásan. Ìjàjàgbara nítorí ìwọ̀sí tó máa ń wáyé látọwọ́ àwọn tí a jẹgàba lórí wọn ló sáábà máa ń bí àwọn akínkanjú jagunjagun nílẹ̀ adúláwọ̀ (ilẹ̀ Áfíríkà). Àpilẹ̀kọ yìí ṣe àgbéyẹ̀wò ìdìtẹ̀mọ́ní látọwọ́ àwọn ọmọ ogun sí Balógun wọn nípa bí àwọn ọmọ ogun Lísàbí ṣe dìtẹ̀ mọ́ ọn láti dójú ìjà kọ ọ́ lẹ́yìn tí wọ́n jagun-ṣẹ́gun tán. Èyí hàn nínú ìwé ìtàn àròsọ Lísàbí Agbòǹgbò Àkàlà nílẹ̀ Abẹ́òkúta tí Olú Owólabí kọ. Ọ̀tẹ̀ dídì mọ́ àwọn asíwájú wọ̀nyí máa ń já sí ikú fún wọn tí omi á wá tẹ̀yìn wọ ìgbín wọn lẹ́nu gẹ́gẹ́ bó ṣe rí fún Lísàbí.  Àpilẹ̀kọ yìí ṣàmúlò ọ̀nà ìwadìí Aṣàpèjúwe àti Tíọ́rì Ìmútànsọ Tuntun (Descriptive Methodolgy and New Historicism Theory) láti ṣe àtúpalẹ̀ àpilẹ̀kọ yìí, èyí tó sì ṣàfihàn wí pé kí ó tó di pé àwọn Òyìnbó aláwọ̀ funfun dé ni ìjẹgàba, ìyannijẹ, ìdàlúrú àti onírúurú ogun ìletò-sí-ìletò, abúle-sí-abúlé àti ilú-sí-ìlú ti wà. Ibi ni àwọn ọmọlẹ́yìn máa ń sáábà fi sú asáájú wọn gẹ́gẹ́ bó ṣe rí fún Lísàbí. Iṣẹ́ yìí wá fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé lópin ìgbà tí àwọn ọmọ ogun bá ń dìtẹ̀ mọ́ asíwájú, iná ìdàgbàsókè àwùjọ kìí jò geere rara.

****** 

A guerra não é como um casamento, nem como dormir com uma mulher que acaba de dar à luz. A história demonstrou isso de várias maneiras, por meio das matanças, da escravidão e da opressão impostas por governantes a cidades que careciam de força suficiente — muitas vezes devido ao orgulho ou à inveja de terceiros. A rebelião contra a opressão exercida pelos dominadores costuma forjar guerreiros valentes no mundo negro (África). Este artigo examina a conspiração de soldados contra seu Comandante-em-Chefe, analisando como as tropas de Lisabí se voltaram contra ele após uma vitória conquistada. Tal fato é evidente na história de Lisabí Agbongbbo Akála, na terra de Abéokuta, narrada por Olu Owólabí. Rebeliões contra esses líderes frequentemente resultavam em suas mortes, com eles sendo forçados a recuar até que a água lhes entrasse pela boca — como ocorreu com Lisabí. O estudo utiliza metodologia descritiva e a teoria do Novo Historicismo para demonstrar que, antes da chegada dos brancos (*Oyinbo*), já existiam dominação, opressão, caos e diversos conflitos entre assentamentos, vilarejos e cidades. Era nesse contexto que liderados frequentemente derrotavam seus líderes, como aconteceu com o caso de Lisabí. O trabalho confirma que, quando soldados estão à frente do poder, a chama do desenvolvimento social jamais brilha com intensidade.

Downloads

Não há dados estatísticos.

Biografia do Autor

Michael Ọláńrewájú AGBOỌLÁ , Kwara State University -Nigeria

is an Associate Professor of Theory and Criticism, in the Department of Performing Arts and Film Studies, Faculty of Arts, Kwara State University (KWASU), Malete, Nigeria. He attended the University of Ilorin, Nigeria, between 1982 and 1986, where he earned his Bachellor of Arts (B.A.) degree in Performing Arts. He obtained two masters degrees, one in Industrial Relations and Personnel Management (University of Lagos, 1991) and the other in Performng Arts (University of Ilorin, 2009), and a  doctoral degree  in Performing Arts (University of Ilorin, 2022). He has published sholarly papers and well-researched articles in both local and international journals. He is the current head of his department.

Referências

Adetola, O. B., Oyedeji, J. K., Oyekunle-Ooniyi, C. O., & Ogunola, A. A. (2023). Nature and dynamics of peace and conflicts in Yoruba land: A qualitative scoping review. The Nigerian Journal of Sociology and Anthropology, 21(1), 13-38.

Agboọlá, M. O. (2021). Politics of space in selected plays of Irene Salami-Agunloye and Emmy Idegu. PhD Thesis, University of Ilorin (unpublished).

Akinwale, G. (2026). Balógun Àjàyí Ògbóríẹfọ̀n and the Battle that saved Ikirun in 1878.

Balogun Ajayi Ogboriefon and the Battle That Saved Ikirun in 1878 | Historical Nigeria.

Balkaya, M. A. (2014). Basic principles of new historicism in the light of Stephen Greenblatt’s resonance and wonder and invisible bullets. European Academic research, 2(5). 7068-7078.

Carrier, N., & Nyamweru, C. (2016). Reinventing Africa’s national heroes: The case of Mekatilili, a Kenyan popular heroine. Africa Affairs. 1-22. Doi: 10.1093/afraf/adw051. http://afraf.oxfordjournals.org/.

Fubah, M. A., Kunda, C. J., Kabelenga, I., & Wihbongale, L. A. (2024). Visualising the iconography of anti-colonial and anti-apartheid heroes and heroines in Tshwane (Pretoria), South Africa, visual studies, 1-9. https://doi.org/10.1080/1472586X.2024.2381096.

Goin, J. (n.d.). Characteristics of a hero. Motivated Magazine, volume 5, issue 1, page 3.

Jones, M. (2007). What should historians do with heroes: Reflections of the nineteenth- and twentieth-century Britain. History Compass, 5(2), 439-454.

Korte, B., & Wendt, S. (2019). Introduction: Studying heroism from a global perspective. In B. Korte, S. Wendt, and N. Falkenhayner. (eds.), Heroism as a Global Phenomenon in Contemporary Culture (pp. 38-60). New York: Routledge.

Lyu, X. (2021). An introduction to new historicism. Advances in Social Science, Education and Humanities Research, volume 543. Proceedings of the 2021 6th International Conference on Social Sciences and Economic Development (ICSSED 2021).

Obi-Onwurah, C. (2026). Unsong Igbo heroes of pre-colonial history: Leaders, warriors, and Visionaries. https://nnewicity.com/unsung-igbo-heroes-of-pre-colonial-history/.

Owólabí, O. (1977). Líṣàbí Agbòǹgbò-Àkàlà. Ibadan: University Press.

Ritter, E. A. (1971). Shaka Zulu: The rise of the Zulu Empire. The Book Club Asscoiates, by arrangement with Longman Group Ltd.

Thompson, O.O., Nwaorgu, O. G. F., & Aduradola, R. R. (2019). Remembered or dismembered, deified or defied? The challenges of African heroines in contemporary history. LWATI: A Journal of Contemporary Research, 16(1), 94-115.

Travelwaka (2020). Moremi statue of liberty, the story of tallest statue in Nigeria. Moremi Statue of Liberty, The Story of Tallest Statue in Nigeria - TravelWaka.

Ujorha, T. (2013). Ile-Ife: The legend of Moremi. Daily Trust online. Ile-Ife: The Legend Of Moremi - Daily Trust.

Veenstra, J. R. (1995). The new historicism of Stephen Greenblatt: On poetics of culture and the interpretation of Shakespeare. History and Theory, 34(3). 174-198. https://www.jstor.org/stable/2505620.

Waller, R. (2008). Review of the book, War in Pre-Colonial Eastern Africa. African Studies Review 51(3), 178-179. https://dx.doi.org/10.1353/arw.0.0112.

Downloads

Publicado

27-08-2026

Como Citar

AGBOỌLÁ , M. Ọláńrewájú. (2026). Ìdojúkọ Àwọn Akínkanjú Jagunjagun Ilẹ̀ Adúláwọ̀ Lọ́wọ́ Àwọn Ọmọ-Ogun Wọn: Lísàbí Agbòǹgbò-Àkàlà láti Owọ́ Olú Owólabí Gẹ́gẹ́ Bí Àpẹrẹ: O Confronto dos Bravos Guerreiros Negros às Mãos de Seus Soldados: O Estupro das Ambongbo-Akala por Olu Owolabi como Exemplo. JINGA SEPÉ: evista nternacional e ulturas, Línguas fricanas rasileiras (ISSN: 2764-1244), 6(Especial II), 79–92. ecuperado de https://revistas.unilab.edu.br/njingaesape/article/view/2906