Ọ̀rọ̀ jẹ́ńdà àti ìjákọní nínú ewì Ọláńrewájú Adépọ̀jù
Gênero e sexualidade na poesia do poeta multifacetado
Mots-clés :
Akọnibnrin, Akọnikùnrin, Ewì, Jẹ́ńdà, Ọláńrewájú Adépọ̀jùRésumé
Àwọn ẹ̀dá ènìyàn tí ó bá kó ipa tí ó ta yọ láàrin àwùjọ ni àwọn Yorùbá ń pè ní akọni. Lọ́pọ̀ ìgbà, àwọn ọkùnrin ni àwùjọ máa ń fojú sùn nígbà tí wọ́n bá ń sọ̀rọ̀ nípa ìjákọni nítorí ìgbàgbọ́ wọn nípa pé agbára ti ọkùnrin ju ti obìnrin lọ. Àwọn afọ̀ ẹnú Yorùbá fi hàn ìjákọni ọkùnrin àti obìnrin nípa wíwo ipa wọn nínú àwùjọ. Ọ̀kan nínú àwọn akéwì tí ó ṣe àgbéjáde irúfẹ́ afọ̀ yìí ni Ọláńrewájú Adépọ̀jù tí ó jẹ́ gbajúgbajà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni Ọláńrewájú Adépọ̀jù. Nípa fífi èdè Yorùbá ké ewì fún àwọn olùgbọ́ rẹ̀, ọ̀rọ̀ nípa jẹ́ńdà àti ìjákọni máa ń jẹ yọ ewì rẹ̀. Ìlepá ìṣẹ́ yìí ni láti wo ìjẹyọ akọnìyàn àti abonìyàn gẹ́gẹ́ bí akọnikùnrin àti akọnibìnrin nínú ewì Ọláńrewájú Adépọ̀jù. Iṣẹ́ yìí ṣe àmúlò àwọn àṣàyàn ewì Ọláńrewájú Adépọ̀jù, ó sì ṣe ìtúpalẹ̀ wọn ní ìlànà tíọ́rì Jẹ́ńdà Ajẹmọ́-Ojúṣe ti Judith Butler (Judith Butler’s Gender Performativity Theory). Iṣẹ́ yìí jẹ́ kí ó hàn pé a lè tọ́ka sí akọnikùnrin àti akọnibìnrin nípa ṣíṣe àkíyèsí àbùdá wọn láàrin àwùjọ. Lára àwọn àbùdá bẹ́ẹ̀ tí iṣẹ́ yìí ṣe àfàyọ gẹ́gẹ́ bí ó ṣe hàn nínú ewì Ọláńrewájú Adépọ̀jù ni ogun, ìjà jíjà, àyà níní, owó níní, òògùn níní, ipò nínú ìṣèlú, ipò nínú ẹ̀sìn àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
*******
Os iorubás chamam de heróis as pessoas que desempenham um papel de destaque na sociedade. Frequentemente, a sociedade concentra-se nos homens ao falar de poder, devido à crença de que eles são mais poderosos do que as mulheres. Os poetas iorubás retratam o poder de homens e mulheres ao observar seus papéis na sociedade. Um dos poetas que aborda essa temática de poder é Olanrewaju Adépoju, um poeta popular na Nigéria. Ao utilizar a língua iorubá para recitar poesia ao seu público, ele frequentemente destaca em sua obra a questão de gênero e poder. O objetivo deste estudo é examinar a representação de heróis e heroínas como tais na poesia de Olanrewaju Adépoju. O estudo utiliza poemas selecionados de Olanrewaju Adépoju e os analisa à luz da Teoria da Performatividade de Gênero de Judith Butler. A pesquisa demonstra que heróis e heroínas podem ser identificados pela observação de suas características na sociedade. Entre essas características destacadas na poesia de Olanrewaju Adépoju, encontram-se a guerra, o combate, a coragem, a posse de recursos financeiros, o domínio de conhecimentos medicinais ou mágicos (medicina tradicional), o status político, o status religioso, entre outras.
Téléchargements
Références
Adelegan, A. (2007). Women of Great Virtues. Lagos: Arigbabowo Publications.
Ademuyiwa, A. L. (2014). “Àgbèyẹ̀wò Ọ̀rọ̀ Jẹ́ńdà nínú Ewì Ọláńrewájú Adépọ̀jù”. (A Critical Analysis of Thematic and Stylistic Features in Oríkì of Towns in Òkè-Ògùn). Unpublished B.A. Long Essay, Department of Linguistics and African Languages, Obafemi Awolowo University, Ile-Ife.
Ademuyiwa, A.L. (2017). “Ìtúpalẹ̀ Ìmọ̀ Ìṣọwọ́lò-Èdè nínú Àsàyàn Ewì Ọláńrewájú Adépọ̀jù”. (A Critical Analysis of Stylistic Features in Selected Ọláńrewájú Adépọ̀jù’s Poetry). Unpublished M.A Thesis, Department of Linguistics and African Languages, Obafemi Awolowo University, Ile-Ife.
Adéyẹmọ, O. A. (2011). “Ìtúpalẹ̀ Kókó-ọ̀rọ̀ Ajẹmọ́-Ìṣèlú Nínú Ewì Yorùbá láti inú Fọ́nrán àti Àpilẹ̀ko (1990-2009)”. Ph.D. Thesis, Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University, Ilé-Ifẹ̀.
Àjàyí, F. (2014). “Àgbéyẹ̀wò Àṣàyàn Ewì Ajẹmóṣèlú Ọláńrewájú Adépọ̀jù: Àfihàn ìṣẹ̀lẹ̀ Àwùjọ”. Nínú ẸGIN: Jọ́nà iṣẹ́ Akadá ní Èdè Yorùbá.
Ajíbádé, G.O. (2001). “A Socio-Cultural Analysis of Yorùbá Personal Oríkì (Oríkì Àbísọ)” In Ifẹ̀ Journals of Theory and Research in Education. Ijotre Vol. 6. No. 1, 90–96.
Ajíbádé, G.O. (2009). Finding female Voice. A Socio-Cultural Appraisal of Yorùbá Nuptial Poetry. Rudiger Koppe Verllag Koln. Germany.
Àjùwọ̀n, J. (2017). “Ìtùpalẹ̀ Àṣàyàn Oríkì àwọn Akọnikùnrin àti Akọnibìnrin Yorùbá ní Ìwọ̀-Oòrùn Orílẹ̀-èdè Nàìjíria”, Unpublished Ph.D. Thesis, Department of Linguistics and African Languages, Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University, Ilé-Ifẹ̀.
Akinwumi, P.A. àti Ademuyiwa, A.L. (2024). “Àjùlọ àti Ìjákulẹ̀ Ẹ̀dá-ìtàn nínú àwọn Ìwé Ìtàn- Àròsọ Yorùbá”. LÀÀNGBÀSÀ: Jónà Iṣẹ́ Akadá ní Èdè Yorùbá, University of Lagos. Number 24. 22–36.
Bíòbákú, S.O (1973). Sources of Yorùbá History. Ìbàdàn. O.U.P.
Bódúndé, C. (2001). “Aesthetics, Media and Political Currents in Yoruba Literature” African Language Literatures and Political context of the 1990’s, Bodunde, C. (ed). Germany: Eckhard Breitinger,
Bowra, C.M (1952): Heroic Poetry. New York. Macmillan.
Butler J. (1990). Gender Trouble: Feminism and the Subversion of Identity. Routledge.
Butler J. (1993). Bodies that Matter: On the Discursive Limits of “Sex”. Routledge.
Fọ́lọ́runṣọ́, A. (1997). “Òṣèlú Akéwì nínú Òṣèlú: Àyẹ̀wò Ewì Lánréwájú Adépọ̀jù”, Inquiry in African Languages and Literature, No. 2, 92–102.
Fọ́lọ́runṣọ́, A. (1999). The written Yoruba Poetry (1949-1989): A study in the Sociology of Literature. A Dissertation. Department of Linguistics and African Languages.
Ìṣọ̀lá, A. (1983). Olú Ọmọ. Ìbàdàn: Onibon-Oje Press and Book Industries.
Lloyd, M. (1999). “Performativity, Parody, Politics”. Theory, Culture & Society. Vol16, no.2., 195–213
Ogundipe, S. (2015). “Hybridity and the Construction of Ọlanrewaju Adepọ̀jù’s Poetry”, Ph.D. Thesis. Ọbafemi Awolọwọ University. Ile-Ifẹ.
Okunoye, O. (2010). “Ewì, Yoruba Modernity, and the Public Space” Research in African Literatures. Vol. 41. No.4, 43–64.
Okunoye, O. (2011). “Lanrewaju Adepọ̀jù and the Making of Mordern Yoruba Poetry” Africa. Vol. 81, no.2., 175-203.
Ọlásùpọ̀, A.F., Olúgbèmí, V. àti Adéniran O. (2012). Proverb and Gender Equalities and Equities in African Cultures: Yorùbá Culture as a Case Study. In Global Journal of Human Social Science: A Arts and Humanities, U.S.A Volume 12, Issue 13, Verson I.O., 11–26. Oxford Dictionary (2006).
Rabiu, O.F. (2025). “Àgbéyẹ̀wò Ipa àti Ipò àwọn Ọ̀dọ́ nínú Àṣàyàn Iṣẹ́-ọnà Adébáyọ̀ Fálétí”. (An Examination of Space and Place of Youths in Selected Works of Adébáyọ̀ Fálétí). Unpublished M.A Thesis, Department of Linguistics and African Languages, Obafemi Awolowo University, Ile-Ife.
Salih, S. (2002). Judith Butler. Routledge
Ude, A.A (2006). “Introducing the Concept of Gender”. Paper presented at 5-Day Capacity Building Workshop on Gender Planning, and budgeting for Local Government Personnel in Nigeria. Organized by the Endowed Chair Centre for Gender and Social Policy, OAU, Ile- Ifè.
Téléchargements
Publiée
Comment citer
Numéro
Rubrique
Licence
© NJINGA&SEPÉ: Revista Internacional de Culturas, Línguas Africanas e Brasileiras 2026

Ce travail est disponible sous licence Creative Commons Attribution - Pas d'Utilisation Commerciale - Pas de Modification 4.0 International.
Les auteurs qui publient dans cette revue acceptent les conditions suivantes:
Les auteurs conservent le droit d'auteur et accordent à la revue le droit de première publication, l'œuvre étant simultanément concédée sous licence Creative Commons Attribution License, qui permet le partage de l'œuvre avec reconnaissance de la paternité de l'œuvre et publication initiale dans ce magazine.
Les auteurs sont autorisés à assumer séparément des contrats supplémentaires, pour la distribution non exclusive de la version de l'ouvrage publié dans cette revue (par exemple, publication dans un référentiel institutionnel ou en tant que chapitre de livre), avec reconnaissance de la paternité et publication initiale dans cette revue.
Les auteurs sont autorisés et encouragés à publier et distribuer leurs travaux en ligne (par exemple dans des référentiels institutionnels ou sur leur page personnelle) à tout moment avant ou pendant le processus éditorial, car cela peut générer des changements productifs, ainsi que citation des travaux publiés (voir l'effet du libre accès).