Àgbéyẹ̀wò ìlò òwe àti àlọ́ àpamọ̀ gẹ́gẹ́ bí ilé ìsura àti orísun ìtàn àwọn akọni ìlú ìbàdàn
Uma análise do uso de provérbios e adivinhas como repositório e fonte de histórias sobre os heróis da cidade de Ibadan.
Palabras clave:
Ìtàn-Akọni, Òwe, Àlọ́-Àpamọ, Lítíréṣọ, Tíọ́rì Ṣoṣiọ́lọ́jìResumen
Iṣẹ́ ìwádìí yìí dá lórí àgbéyẹ̀wò ọ̀nà tí lítíréṣọ̀ alohùn bí i òwe àti àlọ́ àpamọ̀ ń gbà ṣe ìṣelọ́jọ̀ àti ìpamọ́ ìtàn àti ipa mọ́nigbàgbé àwọn akọni ìṣáájú fún àwọn tí ó ń bọ̀ lẹ́yìn. Àfojúsùn iṣẹ́ ìwádìí yìí ni láti ṣe àwárí àwọn òwe àti àlọ́ àpamọ̀ to sọ́ nípa ìgbé ayé, ipa àti ìtàn àwọn àkọni ìlú Ìbàdàn. Tíọ́rì tí a gbé iṣẹ́ ìwádìí yìí lé lórí ni tíọ́rí ṣoṣiọ́lọ́jì tí ó rí iṣẹ́ lítíréṣọ bí ìwògbè aṣàwòta ilé ayé. A ṣe àkójọ àwọn èròjà àmúkalẹ̀ fáyẹ̀wò fún iṣẹ́ ìwádìí yìí ni ìlànà fífi ọ̀rọ̀ wá àwọn àgbà ìlú bí mọ́gàjí, baálẹ̀, àwọn olóyè ìlú àti àwọn òǹpìtàn nílùú Ìbàdàn lẹ́nu wò. Yàtọ̀ sí èyí a ṣe àmúlọ̀ àwọn òwe àti àlọ́ àpamọ̀ tí ó wà nínú àwọn ìwé àtẹ̀jáde bí i Akínyẹmi (2015), Olaoye (2012), Owomoyela (2005), Àjàyí (1990) àti Délànà (1983), Àwọ̀n òwe àti àlọ́ àpamọ̀ tí a gbéyẹ̀wò yìí sọ ní ipa mọ́nigbàgbé àti ìgbéayé àwọn akọni Ìbàdàn bí i Iba Olúyọ̀lé, Balógun Ìbíkúnlé, Baṣọ̀run Ògúnmọ́lá, Balógun Àjàyí Ògbórí-ẹfọ̀n, Ìyálóde Ẹfúnṣetán Aníwúrà, Fọ̀kọ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. lórí ìdáábòbò, ìgbélárugẹ́. Ìdàgbàsókè èto ọrọ̀ ajé àti ìṣèlu ilẹ̀ Yorùbá àti ìlú Ìbàdàn ní pàtàkì jùlọ. Ìtúpalẹ̀ àwọn òwe àti àlọ́ àpamọ̀ yìí fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé aríṣe laríkà, àríkà sì ni baba ìrègun, gbogbo ohun tí a bá ṣe lónìí ọ̀rọ̀ ìtàn ni bó dọ̀la. Ní àkótàn, iṣẹ́ ìwádìí yìí fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé lítíréṣọ̀ alohùn bí òwe àti àlọ́ àpamọ̀ jẹ́ ilé ìsura àti orísun ìtàn, èyí tí a lè lo láti ṣe àkójọ ìtàn àwọn akọni ilẹ̀ Yorùbá.
********
Esta pesquisa baseia-se na análise de como a literatura oral — como provérbios e adivinhas — serve para preservar a história e a influência de heróis do passado para as gerações futuras. O objetivo deste estudo é identificar provérbios e adivinhas que narram a vida, a influência e a história dos líderes de Ibadan. A pesquisa fundamenta-se na teoria sociológica que concebe a literatura como um reflexo do mundo. Os materiais de pesquisa foram coletados e analisados por meio de entrevistas com líderes da cidade — incluindo o prefeito, o governador, autoridades municipais e historiadores de Ibadan. Além disso, examinaram-se provérbios e adivinhas presentes em obras de autores como Akínyêmi (2015), Olaoye (2012), Owomoyela (2005), Àjayí (1990) e Délànà (1983). O conjunto de provérbios e adivinhas analisado aborda o impacto da memória e da trajetória de heróis de Ibadan — tais como Iba Oluyôlé, Balógun Íbikunlé, Bashòrun Ógunmólá, Balógun Àjayí Ógborí-éfón, Íyálóde Efúnşetán Aníwura e Fókó, entre outros — na proteção, promoção e desenvolvimento econômico e social da terra iorubá e, especificamente, da cidade de Ibadan. A análise desses provérbios e adivinhas confirma que o criador é o criador e que o criador é o pai da história; tudo o que fazemos hoje torna-se história amanhã. Em suma, este trabalho confirma que a literatura oral, representada por provérbios e adivinhas, constitui um repositório e uma fonte histórica que pode ser utilizada para compilar a história dos heróis iorubás.
Descargas
Citas
Abiodun, M.A. et al (2022). A Sociolinguistic Analysis of Yoruba Names Derived From Proverbs. SKASE: Journal of Literary and Cultural Studies 4(3), 12-30 http://www.skase.sk/volume/SJLC09/04.pdf 2644-5506
Adeboye, O.A. (2003). The City of Ibadan. In G.O. Oguntomisin (Ed.) “Yoruba Towns and Cities Vol.1, 7-19. Ibadan Bookshelf Resources Limited
Adélékè, D. (2020). The Foolery of Man beyond the Theatrical World: Perspectives from an Indigenous African Literary Critic. An Inaugural Lecture Delivered at the University of Ibadan. Ibadan University Press
Adèlékè, D. (2009). Yorùbá Proverbs as Historical Records. Proverbium.26, 19-48.
Ajayi, B. (1990). Òjìlélẹ́gbẹ̀ta Àlọ́ Àpamọ̀. Ilorin: Tawfiqullah Publishing House
Akande, I.D. (2020). On the Pragmatic Implications of Oyo-Related Proverbs in South-western Nigeria, Proverbium, 37, 1-16
Adeniyi, H. (2017). Naming, Names and Praise Names. In Falola, T àti Akinyemi (Olóòtú) Culture and Customs of the Yorùbá o.i.85-98, Pan-African University Press
Akinyemi, A. (2015). Orature and Yoruba Riddles. Palmgrave Macmillian
Awe, B. (1974). Praise Poems as Historical Data: The Example of the Yoruba Oriki. Africa: Journal of the International African Institute, 44 (4), 331-349 https:/doi.org/10.2307/1159054
Danmole, H.O. àti Falola, T. (1985). Ibadan-Ilorin Relations in the Nineteenth Century: A Study in Imperial Struggles in Yorubaland: Transafrican Journal of History, 14, 21-35
Delano, I.O. (1983). Owe Lesin Oro. Ibadan University Press
Fatokun, J.O. (2011). Ibadan in the 20th century: Growth, Influence and Challenges. Spectrum Books
Friday-Otun, J.O. (2014). Anti-Theft Philosophy in selected Yorùbá Proverbs. In A.S. Abdussalam. In (Ed.), Bringing Our Cultures Home: Festschrift for Bádé Àjàyí at 70. Chridamel Publishing House
Ògúnlọlá, L. (2014). Yorùba Proverbs and Morality (ìwà ọmọlúàbí): the Past, Present and the Future in Abdussalam, A.S et al (Eds). Bringing Our Cultures Home: Festschrift For Bade Ajayi At 70. Chrimadel Publisher.
Ogunsina, J.A. (2006). The Sociology of Yorùbá Novel. 1930-1975. Integrity Publication
Ògúnwálé, A. (2016). Naming in Yorùbá: A Sociolinguistics Exposition. Obafemi Awolowo University Press
Ojo, E.T. (2015). Predominant Stylistic Devices of Proverbs in Selected Yorùbá Literary Texts. Yorùbá: Journal of Yorùbá Studies Association of Nigeria, 8(1), 253-292
Oladeji, K. àti Popoola, B. (2024). A Morphological Analysis of Selected Ibadan Place Names: Documenting and Preserving its Linguistics and Cultural Heritage. Opanbata: LASU Journal of African Studies, 12, 172-191
Olaoye, J.S. (2012). Principles and Concepts of Yoruba Language and 1,122 Yorùbá Proverbs. Famost Printmedia
Olatunji, O.O. (1984) Features of Yoruba Oral Literatures. Ibadan: UPL
Olawale, F.I. àti Ogunbode, S.A. (2016). Gender and the Politics of Exclusion in Pre-Colonial Ibadan: The Case of Iyalode Efunsetan Aniwura. Journal of Traditions and Beliefs Volume 2
Olawale, S.B. (2012). Slaves, Government and Politics in Ibadan, 1835-1893. IOSR Journal of Humanities and Social Sciences (JHSS), 3(6), 13-17 https://www.Iosrjournals.org
Vanguard, July 23 (2016). “Sanusi Adebisi Idikan- (1882-1938) First Ibadan Notable Entrepreneur and Philanthropist
Orímóògùnjẹ, O.C. (2015). Socio-Mythical Approach to Yoruba Indigenous Health Related Verbal Art. Ilorin Journal of Linguistics, Literature and Culture Vol 5.
Owomoyela, O. (2005). Yoruba Proverbs. University of Nebraska Press
Rabiu, R.A. (2024). Place Names as Source Materials in the Derivation of Selected Yorùbá Riddles: A Sociological Approach. Journal of Linguistics, Culture and Communication, 2(2),89-107https://doi.org/10.61320/jolcc.v2i2.89-107 https://jolcc.org
Watson, R. (1999). Ibadan- a model of historical facts’: Militarism and civic culture in a Yoruba City. Urban History, 26(1), 5-26
Descargas
Publicado
Cómo citar
Número
Sección
Licencia
Derechos de autor 2026 NJINGA&SEPÉ: Revista Internacional de Culturas, Línguas Africanas e Brasileiras

Esta obra está bajo una licencia internacional Creative Commons Atribución-NoComercial-SinDerivadas 4.0.
Los autores que publican en esta revista aceptan los siguientes términos:
Los autores mantienen los derechos de autor y otorgan a la revista el derecho a la primera publicación, siendo el trabajo simultáneamente licenciado bajo la Licencia de Atribución Creative Commons, que permite compartir el trabajo con reconocimiento de la autoría del trabajo y la publicación inicial en esta revista.
Se autoriza a los autores a asumir contratos adicionales por separado, para la distribución no exclusiva de la versión del trabajo publicado en esta revista (p. Ej., Publicación en repositorio institucional o como capítulo de libro), con reconocimiento de autoría y publicación inicial en esta revista.
Se permite y se anima a los autores a publicar y distribuir su trabajo en línea (por ejemplo, en repositorios institucionales o en su página personal) en cualquier momento antes o durante el proceso editorial, ya que esto puede generar cambios productivos, así como aumentar el impacto y cita del trabajo publicado (Ver El efecto del acceso abierto).