Àfihàn obìnrin nínú àwo̩n àsàyàn orin àlo̩ onítàn Yorùbá
A representação das mulheres nas canções folclóricas iorubás
Palabras clave:
Obìnrin, Orin, Àló̩ Onítàn, Ìfojú-Ìhun-WoResumen
ÀSAMÒ̩
Ò̩kan pàtakì lára ewì alohùn Yorùbá ni àló̩ onítàn jé̩. Àló̩ wà fún ìdárayá, ìgbádùn àti ìdánilé̩kò̩ó̩. Ò̩gò̩ò̩rò̩ is̩é̩ ìwádìí ni àwo̩n onímò̩ ti s̩e lórí àló̩ onítàn Yorùbá s̩ùgbó̩n kò fi bé̩è̩ sí è̩yí tí ó sò̩rò̩ nípa obìnrin. Ló̩nà àti dí àlàfo yìí, a lo tíó̩rì ìfojú ìhun wò èyí tí ó so̩ pe lítírésò̩ lè ní ìtumò̩ tí ó gbòòrò ju e̩yo̩ ò̩rò̩, gbólóhùn tàbí ohun tí ó wà ní ojú ìwé lo̩ èyí tí Ferdinand Sassure s̩e agbáte̩rù rè̩ s̩e àtè̩gùn láti s̩e àfihàn obìnrin nínú àwo̩n àsàyàn orin àló̩ onítàn Yorùbá. Ó hàn gbangba pé ò̩nà méjì gbòòrò ni a gbà fi obìnrin hàn nínú àwo̩n àló̩ onítàn Yorùbá. Ló̩nà kíní a fi obìnrin hàn gé̩gé̩ bí aya rere, abiamo̩ tòótó̩, àti oníwà rere, bákan náà ni a tún fi obìnrin hàn gé̩gé̩ bí òjòwú, ò̩dájú àti ìkà. Ìgúnlè̩ is̩é̩ ìwádìí yìí ni pé lòdì sí ohun tí àwùjo̩ ń so̩ nípa obìnrin kìí s̩e pátápátá ni ò̩pò̩ló̩ obìnrin kò nírù, bé̩è̩ ni kìí s̩e pé kò sí is̩é̩ rere kankan ló̩wó̩ àwo̩n obìnrin. Fún ìdí èyí, ojú àìsègbè tí a fi wo obinrin nínú àwo̩n àló̩ onítàn Yorùbá ni ó yè̩ kí àwùjo̩ s̩e àmúlò, kí wó̩n fi ahó̩n rere pe obìnrin ni ibi tí ó bá ti ye̩, kí ìtè̩síwájú àti ìdàgbàsókè lè wà láwùjo̩.
*******
Um dos aspectos mais importantes da poesia vocal Yorùbá é a história. A história serve para entretenimento, prazer e educação. Estudiosos realizaram pesquisas sobre a história Yorùbá, mas não se concentraram na história das mulheres. Para preencher essa lacuna, utilizamos a teoria da percepção visual, que afirma que a literatura pode ter um significado mais amplo do que as palavras, frases ou objetos na página que Ferdinand Sassure usou para descrever as mulheres nos poemas selecionados da história Yorùbá. É evidente que existem duas maneiras amplas pelas quais as mulheres são retratadas no folclore Yorubá. De um lado, as mulheres são retratadas como boas esposas, mulheres honestas e mulheres virtuosas, e de outro, as mulheres são retratadas como ciumentas, invejosas e cruéis. A conclusão deste estudo é que, ao contrário do que a sociedade diz sobre as mulheres, elas não são completamente impotentes, nem que elas não tenham boas ações. Por essa razão, a visão imparcial das mulheres no folclore iorubá é importante para que a sociedade adote, para dar às mulheres um nome positivo ao qual elas pertencem, para que o progresso e o desenvolvimento possam ocorrer na sociedade.
Descargas
Citas
Acholonu, R. (1999). “Women in the African Novel and the Quest for Human Rights” in Beyond the Marginal Land, Opara, C. (ed.) PortHarcourt: Belpot.
Adébáyọ̀, A. (ed.) (1996). “Tearing the Veil of Invisibility: the Roles of West African Female Writers in Contemporary Times” in Feminism and Black Women’s Creative Writing. Ìbàdàn: AMD Books.
Akóredé, Y. O. (2011). Feminism and Literature: Womanism and the Intra-Gender Conflict Theory. Republic of Benin: National Library Publishing (ESAF).
Amo̩o (2010) Àkójo̩pò̩ Àló̩ Àpagbè. Os̩ogbo: Mabol Trust publishers.
Babalọla (1974). “Àkójọpọ̀ Àlọ́ Ìjàpá Apá Kìn-ín-ní” University Press PLC.
Babatunde (1994) Obìnrin Nínú Ìṣèlú Ilẹ̀ Yorùbá, Department of Linguistics and African Languages, University of Ibadan, Ibadan.
Bádé Àjàyí (2015). Ìtúpalẹ̀ Àlọ́-Àpamọ̀ Yorùbá. Unilorin Press, University of Ilorin, Nigeria.
Bascom (1940). “Literary style in Yorùbá Riddles”, Journal of American Folklore, Vol. 20, No. 1:1-32.
Bọ̀dé Agbájé (2013). Àlọ́ Nínú Àṣàyàn Yorùbá. Elyon publishers.
Culler Jonathan (1975). Struturalist Poetics, Structuralism Linguistics and Literature, New-York. Cornell University Press.
Fasehun, M.A. (2009). “Àtúnyẹ̀wò ohun tí Ifá Sọ Nípa Obìnrin” nínú Láàńgbàsà (Jọ́nà Iṣẹ́ Akadá Ní Èdè Yorùbá). University of Lagos. Lagos: JOYTAL.
Fasehun, M.A. àti Òjó, I. F. (2015). “Obìnrin ni Ọ̀tá Ara Rẹ̀” nínú Baawà: Jọ́nà Ẹ̀ka Ẹ̀kọ́ Èdè Yorùbá, Fọ́lúùmì 1, Nọ́ńbà 1, o.i. 89-95.
Ilésanmí, T.M. (2013). Obìnrin: A Cultural Assessment of Yorùbá Woman. Nigeria: Astra Multimedia Nig. Ltd.
Kọ́láwọlé, M.E.M. (1987). Woman and African Consciousness. Trenton, New Jersy: African World Press.
Ọbáfẹ́mi, Olu, (2008). “Gender Politics and Theory in a Democratic Culture: The Nigerian Female Writers Perspectives.” nínú Olú Ọbáfẹ́mi, Public Discourse in Humanities. Ibadan: University Press Plc. o. i. 79-88.
Ògúndípẹ̀-Leslie, O. (1984). ‘Not Spinning on the Axis of Maleness’ Morgan, R. (ed.) Global New York: Anchor Double Day.
Ojo, O̩lagoke (2005) Ìjàpá Tìrókò O̩ko̩ Yánníbo. Lagos:Learn Africa Plc.
Ọlabimtan, A. (1982). “Form and Meaning in Yorùbá Riddles”, Nigeria Magazine No. 140:66-76.
O̩padotun, O. (1994). Àsàyàn Àlọ́ Onítàn. Ibadan: Y-Book.
Ọ̀pẹ́fèyítìmí, A. (2009). Women in Yorùbá Culture: A Dozen of Academic Articles. Nigeria: Penthouse Publications (Nig.).
Yai, O. (1977). Some Structural Aspext of Yorùbá Alo-Àpamọ̀ (Riddles)”, Seminar series part II. Oyelaran (ed.) 419-62.
Smith, (1985). “Racism and Women’s Studies” Hull, G., Scot, P.B. & Smith, B. (eds.)
Descargas
Publicado
Cómo citar
Número
Sección
Licencia
Derechos de autor 2025 NJINGA&SEPÉ: Revista Internacional de Culturas, Línguas Africanas e Brasileiras

Esta obra está bajo una licencia internacional Creative Commons Atribución-NoComercial-SinDerivadas 4.0.
Los autores que publican en esta revista aceptan los siguientes términos:
Los autores mantienen los derechos de autor y otorgan a la revista el derecho a la primera publicación, siendo el trabajo simultáneamente licenciado bajo la Licencia de Atribución Creative Commons, que permite compartir el trabajo con reconocimiento de la autoría del trabajo y la publicación inicial en esta revista.
Se autoriza a los autores a asumir contratos adicionales por separado, para la distribución no exclusiva de la versión del trabajo publicado en esta revista (p. Ej., Publicación en repositorio institucional o como capítulo de libro), con reconocimiento de autoría y publicación inicial en esta revista.
Se permite y se anima a los autores a publicar y distribuir su trabajo en línea (por ejemplo, en repositorios institucionales o en su página personal) en cualquier momento antes o durante el proceso editorial, ya que esto puede generar cambios productivos, así como aumentar el impacto y cita del trabajo publicado (Ver El efecto del acceso abierto).