Àgbéyè̩wò orísirísi ìlò èdè tí ó je̩yo̩ nínú ìwé ìtàn àròsọ kò sọ́rọ̀ tí layọ̀ ògúnlọlá kọ

Auteurs

Résumé

Ìlò èdè Yorùbá láàrin àwọn ọmọ káàárọ̀-oò-jíire tí n di ohun àfìṣẹ́yìn tí éégún n fisọ. Ìdí gan nìyí tí olùwádìí ṣe gùnlé kókó iṣẹ́ yìí láti ṣe àwárí àwọn àkànlò èdè ayàwòrán tó forí nù jáde ní pàápàá jùlọ nínú ìwé Ìtàn Àròsọ Kò Sọ́rọ̀. Iṣẹ́ yìí ṣe àwárí àwọn àkànlò-èdè bíi ìyán-ọ̀rọ̀-fẹ́rẹ́, ìṣewẹ́kú, ìfìrógbòyeyọ, ìfìrómọrísì, ìfìrósínrójẹ, ìfohùnpènìyàn, òwe, ìfènìyànpohun àti àfiwé tààrà. Iṣẹ́ àpilẹ̀kọ yìí ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn ìlò èdè wọ̀nyí nípa lílo tíọ́rì soṣíọ́lọ́jì lítíréṣọ̀ tó tẹ̀lé èrò Karl Marx. Ní ìparí, iṣẹ́ yìí dábàá fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó n kọ́ ẹ̀kọ́ Yorùbá, àwọn olùfẹ́ èdè Yorùbá, àwọn ilé iṣẹ́ rédíò àti tẹlifísàn tí ń gbé èdè Yorùbá lárugẹ láti máa ṣe àmúlò àwọn àkànlò èdè ayàwòrán wọ̀nyí nínú ìgbòkègbodò wọn lójoojúmọ́, nípa síṣe èyí, èdè wa kò ní lọ sí oko ìparun.

Téléchargements

Les données relatives au téléchargement ne sont pas encore disponibles.

Biographie de l'auteur

Akinniyi Williams AKINLABI, Federal College of Education, Yola, Adamawa State

Department of yorùbá, Federal College Of Education, Yola, A Yoruba lecturer from Federal College of Education, Yola, Adamawa State. I have been a tutor for the past eighteen years. Presently I am undergoing my doctorate degree at Department of Linguistics and African Languages, university of Ibadan in Yoruba literature

Références

Adéyẹmí, L. (2006). Tíọ́rì Lítíréṣọ̀ ní Èdè Yorùbá: Ìjẹ̀bú Òde: Shebiotimo

Publication.

Adéyẹmọ, O. (1997). Obìnrin Nínú Eré Onítàn Ládojúdé: Rẹ́rẹ́ Rún àti Abẹ́rẹ́

Oró Bí Àpẹẹre, M.A Project: Ìlọrin, University ofÌ lọrin.

Adéọ̀sun, H. O. (2005). Lítíréṣọ̀ àti ètò ọrọ̀ ajé àwùjọ nínú àwọn ìwé ìtàn

àròsọ Fágúnwà. M.A Project University of Ilorin, Ilorin.

Agu, I. E. (2008). Introduction to literary criticism. Yola: Paraclete Publishers.

Eagleton, T. (1996). Literary theory: An introduction (2nd Edition).

Minneapolis: University of Minnesota Press.

Gidden, G. (2006). Sociology. Ibadan: Polity Success Consult.

Ògúnlọlá, L. (2013). Kò sọ́rọ̀. Ì lọrin: Chridamel Publishing House.

Oyèrìndé, O. àti Álímì, K. (2011). ÀKànlò èdè Ayàwòrán nínú Lítíréṣọ̀ Yorùbá: Máyàmí fún olùkọ́ àti akẹ́kọ̀ọ́. Ibadan: Standard Publication.

Ọ̀pẹ̀fèyítìmí, A. (1997). Tíọ́rì àti ìsọwọ́lò-èdè. Òṣogbo: Tanimẹ̀yìn-Ọ̀la Press.

Téléchargements

Publiée

13-08-2025

Comment citer

AKINLABI, A. W. . (2025). Àgbéyè̩wò orísirísi ìlò èdè tí ó je̩yo̩ nínú ìwé ìtàn àròsọ kò sọ́rọ̀ tí layọ̀ ògúnlọlá kọ. NJINGA&SEPÉ: evista nternacional e ulturas, Línguas fricanas rasileiras, 5(Especial II), 143–153. onsulté à l’adresse https://revistas.unilab.edu.br/njingaesape/article/view/2385