Àfihàn agbára èṣù nínú àsàyàn ewì ajẹméṣù
The Reflection of Èṣu’s Power in the Selected Èṣù-Related Poetry
Mots-clés :
Èṣù, Èsè-Ifá, Lítíréṣọ̀ Alohùn Yorùbá, tíọ́rì ìfojú ìmọ̀-ìbára-ẹni-gbé-pọ̀-wo lítíréṣọ̀Résumé
Isé yìí ṣe àfihàn agbára Èṣù nínú ewì ajẹméṣù. Iṣẹ́ yìí tún ṣe ìtúpalẹ̀ bí agbára Èṣù ti ṣe jẹyọ nínú àṣàyàn ewì-ajẹméṣù pàápàá jùlọ ẹṣẹ-Ifá. A ṣe èyí pẹ̀lú èrò láti ṣ̣àlàyé àgbékalẹ̀ àti àkóónú ewì ajẹméṣù gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe wà nínú ẹsẹ Ifá àti àlàyé nípa àbùdá agbára Èṣù. Abala méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní ọgbọ́n ìṣèwádìí tí a lò nínú iṣẹ́ yìí. Abala àkọ́kọ́ ni a ti ṣe ìfọ̀rọ̀wáni-lẹ́nu-wò fún àwọn Babaláwo, àwọn olùsìn Èṣù àti àwọn apohùn ìbílẹ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun àti Ọ̀yọ́. Ìdí tí a fi ṣe àṣàyàn ìpínlẹ̀ wọ̀nyí ni pé, ibẹ̀ ni a ti lè rí àwọn ìlú ìṣẹ̀ǹbáyé tí a ti lè rí ewì ajeméṣù gbà ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́. Ní abala kejì ọgbọ́n ìṣèwádìí yìí ni a ti yẹ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìwé tí ó wúlò fún iṣẹ́ ìwádìí yìí wò bí i; àwọn ìwé Ifá, átíkù inú jọ́nà àti ìtàkùn àgbáyé. Àwọn àkójọ-èdè-fáyẹ̀wò wọ̀nyí ni a ṣe ìtúpalẹ̀ wọn pẹ̀lú tíọ́rì àbùdá oníbejì. Àbájáde iṣẹ́ yìí fi Èṣù hàn gẹ́gẹ́ bí Òrìṣà ti ó lágbára àyínìke àti àyínnìpadà, tí ó sì ń pè fún ìdájọ́ òdodo àti àyípadà rere. dípò ojú aṣebi tí àwọn èsìn àjèjì fi wò ó. Iṣẹ́ yìí ṣe àfikún ìmọ̀ tí ó ti wà nílẹ̀ tẹ́lẹ̀ lórí lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá, ìmọ̀ abínibí Yorùbá àti láti ṣe àtunṣe sí èrò àti ìgbàgbọ́ àwọn ẹ̀sìn àjèjì nípa Èṣù.
*****
This study examines the reflection of Èṣù’s power in the selected Èṣù-related poetry, analyzing how the deity's influence is embedded in the Yoruba oral poetry, most especially Ifá literary corpus. The research adopts both primary and secondary sources of data collection. The primary data were obtained through in-depth interviews with Ifá priests, Èṣù worshipers and traditional orature in Ọ̀ṣun and Ọ̀yọ́ states, Southwestern Nigeria, to collect Èṣù-related poetry that encapsulates the power and role of Èṣù divinity. Secondary data were gathered from relevant Ifá texts, scholarly articles, and online resources. The collected data were transcribed and analyzed within the theoretical framework of binary complementarity, which emphasizes the dual yet interdependent nature of forces in literature, culture, and societal structures. Findings reveal that Èṣù embodies the principle of duality, functioning as both a positive and negative force -an agent of balance, mediation, and transformation within the esu-related poetry, especially Ifá literary tradition. This challenges colonial distortions that depict Èṣù as purely malevolent. The study contributes to the discourse on Yoruba oral literature, indigenous knowledge systems, and the nuanced reinterpretation of African religious traditions in contemporary scholarship.
Téléchargements
Références
Abímbọ́lá, W. (1968). Ìjìnlẹ̀ ohùn ẹnu Ifá. Apá kìíní. Glasgow: Collins.
Adékúnlé, D. (2002). Èṣù Oduism The Transcendental Orthodox Religion of Òduà Race. Ilé-Ifẹ̀, Ọ̀ṣun State Secretariat.
Aiyejina, F., (2009). “Èṣù ẹlẹ́gbára: a source of an alternative theory of African literature and criticism”. Retrieved from www.researchGate/google search.com on 25th January, 2018.
Ajíbádé, G.O., (2009). Finding female voice: A social-cultural appraisal of Yorùbá Nuptical Poetry. Germany: Rudiger Koppe Verlag Koln.
Àlàbá, O., (2004.). “Àṣàrò lórí méjì nínú oríkì láaróyè (Èṣù)”. Láàńgbàsà: Journal of Department of Linguistics and Asian Studies.
Alana, O., (2004). “Traditional religion”. Nínú (Eds.) Lawal, Nike. S, Sadiku Mathew. N, and Dọ̀pámú, Adé. Understanding Yorùbá life and culture. Trenton, NJ: African World Press, o.i. 65-80.
Anita, P., & Paulus, S., (2016). “Saussurian binary opposition as the narrative structure of Williams’ Summer and Smoke”. Journal of Department of English Letters. Retrieved from www.e-journal.usd.ac.id/google search.com on 21th October, 2019.
Anton, G., (1981). History of binary and other non-decimal numeration. United states of America: Library of Congress Cataloging in Publication Data. Retrieved from www.book.google search.com on 23th October, 2019.
Asar, I., (2012). “Understanding àṣẹ and its relation to Èṣù among the Yorùbá and àṣẹ in ancient Egypt”. The mocha-versity Institution of Philosophy and Research. Retrieved from www.asarimhotep.com/google search on April, 4th 2018).
Barber, K., (1990). “Oríkì: women and the proliferation and merging of Orisha”. Africa: Journal of the International African Institute, Fol.60, o.i. 313-337.
Dọ̀pámú, A., (2000). Èṣù the invisible foe of man. A comparative study of satan in Christianity, Islam and Yorùbá religion. Ìjẹ̀bú-òde: Shebíotimọ Publications.
Euba, F., (1989). Archetypes, imprecators, and victims of fate: Origins and development of satire in Black Drama. New York: Greenwood Press. Retrieved by www.books.google search.com on 30th January, 2018.
Fálọlá, T., (2013) “Yorùbá god, power and the imaginative frontiers”. Nínú Tóyìn Fálọlá (ed) Èṣù: Yorùbá god, power, and the imaginative frontiers. Carolina: Academic Press. Retrieved from www.books.google search.com on 25th January, 2018.
Ìdòwú, E.B., (1962). Olódùmarè: God in Yorùbá belief. African: Tree Press, L.I., NY.
Igboin, B.O., (2019). “Olódùmarè and Èṣù in Yorùbá religious thought”. Yorùbá Studies Review, Fol.4, Nọmba 1, o.i. 209-232.
Ilésanmí, T.M., (1988). “Tíọ́rì àbùdá oníbejì fún àgbéyẹ̀wò lítíréṣọ̀ Ifá”. Nínú YORÙBÁ: Journal of the Yorùbá Studies Association of Nigeria.
Lévís-Strauss, C., (1972). Structure anthropology. Harmondsworth: Penguin.
Kristen, H., (2005). “Theology thursdays: Transformations of Èṣù”. Retrieved by www.book.google search.com on 25th January, 2018.
Ògúnbọ̀wálé, P.O. (1980). Àwọn Irúnmọlẹ̀ Ilẹ̀ Yorùbá. Ìbàdàn: Evans Brothers (Nigeria Publishers) Limited.
Onyibor, M.I., & Eégúnlúsì, T.R., (2019). “A critique of traditional Igbo and Yorùbá moral perspectives of evil”. CSCANADA: Canadian Social Science. Vol 15, No. 3, o.i. 62-72. Retrieved from www.google search.com on Friday 19th, April, 2019.
Ọpẹ́ọlá, S.M., (2001). Odù: A repository of the secret of Òrìṣà Tradition. Ilé-Ifẹ̀: Kabbalah Centre.
Pemberton, J., (1976). “The Yorùbá trickster god”. Nínú UCLA James S. Coleman African Studies Center. Retrieved from www.google search.com on 17th, May, 2018.
Peter, M., (1997). Hail Orisha! A phenomenology of a West Africa Religion in the Mid-Ninetheenth Century. New York: Brill, o.i. 43-44 Retrieved by
www.google search.com on 25th January, 2018.
Sa’adu, T. (2021). “Àgbékalẹ̀ àti àkóónú ewì ajẹméṣù ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ àti Ọ̀ṣun ní Nàìjíríà (Form
and content of Èṣù-related poetry in Ọ̀yọ́ and Ọ̀ṣun states of Nigeria, (Doctoral
dissertation Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University, Ilé-Ifẹ̀.)
Simpson, G.E., (1994). Yorùbá religion and medicine in Ìbàdàn. Ìbàdàn: University Press.
Téléchargements
Publiée
Comment citer
Numéro
Rubrique
Licence
(c) Tous droits réservés NJINGA&SEPÉ: Revista Internacional de Culturas, Línguas Africanas e Brasileiras 2025

Ce travail est disponible sous licence Creative Commons Attribution - Pas d'Utilisation Commerciale - Pas de Modification 4.0 International.
Les auteurs qui publient dans cette revue acceptent les conditions suivantes:
Les auteurs conservent le droit d'auteur et accordent à la revue le droit de première publication, l'œuvre étant simultanément concédée sous licence Creative Commons Attribution License, qui permet le partage de l'œuvre avec reconnaissance de la paternité de l'œuvre et publication initiale dans ce magazine.
Les auteurs sont autorisés à assumer séparément des contrats supplémentaires, pour la distribution non exclusive de la version de l'ouvrage publié dans cette revue (par exemple, publication dans un référentiel institutionnel ou en tant que chapitre de livre), avec reconnaissance de la paternité et publication initiale dans cette revue.
Les auteurs sont autorisés et encouragés à publier et distribuer leurs travaux en ligne (par exemple dans des référentiels institutionnels ou sur leur page personnelle) à tout moment avant ou pendant le processus éditorial, car cela peut générer des changements productifs, ainsi que citation des travaux publiés (voir l'effet du libre accès).