Ọ̀pẹ Ìjàyè ló le ròyìn ogun Ògúnmọ́lá": Ààrẹ Kúrunmí àti ìjìjàdù rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí akọni málegbàgbé

"A Palma da Vitória Pode Contar a História da 100ª Guerra": O Presidente Kurunmi e Sua Luta como Herói de Malegbage

Autores/as

Palabras clave:

Ààrẹ Kúrunmí, akọni málegbàgbé, ìfojú-ìmọ̀-ìtàn-wò, ìjìjàdù, Yorùbá

Resumen

Òfin tí ó de ipò lọ́balọ́ba ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ kò to Oníjàyè ìlú Ìjàyè sí ipò Ọba Onípò Kìn-ín-ní gẹ́gẹ́ bí Olúbadàn, tí ó sì jẹ́ pé ipò pàtàkì ni ìpò yìí látijọ́ rí. Ohun tí èyí tọ́ka sí ni pé ojú yẹpẹrẹ ni àwọn ènìyàn àsìkò yìí fi wo àwọn alágbára tí ó jẹ́ pé ìlú wọn kò tóbi mọ́ ní òde-òní. Òtítọ́ ni pé ìlú Ìjàyé kò tóbi báyìí ṣùgbọ́n ìwádìí yìí fi múlẹ̀ pé ipò pàtàkì ni ipò Baálẹ̀ ìlú náà lásìkò Kúnrunmí Àjàdí Ìdẹ. Ìdí nìyí tí ìwádìí náà ṣe yàn láti walẹ̀jìn lórí bí ìṣòtítọ́ àti ìwà akínkanjú ṣe sọ Kúrunmí di akọni málegbàgbé ní ilẹ̀ Yorùbá. Láti inú àwọn ìwé ìtàn ilẹ̀ Yorùbá àti ìtàn ogun wọn ni olùwádìí ti ṣe àkójọ àwọn détà ìpílẹ̀ tí a túpalẹ̀ nínú ìwádìí yìí. A ṣe àmúlò ohùn tí a gbà sílẹ̀ náà fún àfikún. Orí tíọ́rì ìfojú-ìmọ̀-ìtàn-wò ni olùwádìí gbé àlàyé détà lé. Ìlànà agbàròkọ pọ́nńbélé sì ni a fi ṣe àlàyé àwọn détà náà. Àbọ̀ ìwádìí fi hàn pé olùgbèjà ìran àti àṣà Yorùbá ni Kúrunmí; ó jẹ́ olùgbèjà mẹ̀kúnnù; olódodo àti atẹ̀lénimáyà. Orí ìṣòdodo yìí ni ó sì kú lé gẹ́gẹ́ bí akọni málegbàgbé. Ìwádìí fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ìtàn ìlú Ìbàdàn, ìtàn oyè Aláàfin àti ti ilẹ̀ Yorùbá kò tí ì pé láì mẹ́nu bá ìjìjàdù Kúrunmí Àjàdí Ìdẹ gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ-ọ̀nà Kakaǹfò ilẹ̀ Yorùbá. Ìwádìí dábàá pé àmúlò ẹ̀rọ awalẹ̀pìtàn máa jẹ́ kí á ní ìdánilójú lórí àwọn ìtàn àtẹnudẹ́nu tí a ti dàkọ lóde-òní. 

****** 

A lei que estabeleceu o status das chefias tradicionais no Estado de Oyo não elevou o Onijaye de Ijaye ao status de Chefe Supremo, como o Olubadan — uma posição de grande importância no passado. Isso indica que, naquela época, as pessoas menosprezavam figuras poderosas locais porque a cidade já não era mais grande. Embora a cidade de Ijaye não seja grande atualmente, esta pesquisa confirma que o cargo de chefe da cidade era de grande importância durante a época de Kurunmi Ajadi Idde. Por isso, a pesquisa buscou aprofundar-se em como a lealdade e a bravura de Kurunmi o transformaram em um herói lendário nas terras iorubás. O pesquisador compilou os dados básicos analisados ​​neste estudo a partir de livros históricos iorubás e relatos de suas guerras. Registros de relatos orais foram utilizados para obter informações adicionais. A análise dos dados baseou-se na teoria da observação histórica, utilizando-se o princípio da análise narrativa. A pesquisa revelou que Kurunmi foi um defensor da raça e da cultura iorubá, bem como dos pobres; era um homem justo e corajoso. Ele morreu por essa retidão, tornando-se um herói imortal. Ficou estabelecido que a história de Ibadan, a história do Alaafin e a história das terras iorubás estão incompletas se não mencionarem a luta de Kurunmi Ajadi Idde como o Kakañfo (comandante militar supremo) da região. A pesquisa sugere que o uso de tecnologias arqueológicas permitirá validar as histórias orais registradas atualmente.

Descargas

Los datos de descargas todavía no están disponibles.

Biografía del autor/a

Luqman Abísọ́lá KÍARÍBẸ̀Ẹ́, Ọ̀ṣun State University, Òṣogbo, Nigeria

lectures at the Linguistics and Nigerian Languages department, Faculty of Culture, College of Humanities and Culture, Ọ̀ṣun State University, Nigeria. As a specialist in Yorùbá oral poetry, he focuses his research on African oral performatives and sustainable development. Kíaríbẹ̀ẹ́ has publications in reputable journals across the global world.

Citas

Adé-Àjàyí, J.F. and Smith, R. (1971). Yorùbá Warfare in the Nineteenth Century. Ìbàdàn: Ibadan University Press.

Akínjọ́gbìn, A. (1998). War and Peace in Yorùbáland (1793-1893). Ìbàdàn: Heinemann Educational Books (Nigeria) PLC.

Àtàndá, J. A. (2007). A Comprehensive History of the Yorùbá People up to 1800. Ibadan: John Archers (Publishers) Limited.

Dou, P. àti Zhang, K. (2025). "Odysseus’ View on Death and Heroism through his Dialogue with the Ghost of Archilles," Proceedings of the 2024 International Conference on Social Sciences and Educational Department (ICOSSED 2024), Advances in Social Science, Education and Humanities Research, o.i. 490-497.

Ekroth, G. (2002). The Sacrificial Rituals of Greek Hero-cults in the Archaic to the Hellenistic Period. Liège: University of Liège.

Fádípẹ̀, N.A. (1970). The Sociology of the Yorùbá. Ìbàdàn: Ibadan University Press.

Hamilton, P. (2005). Historicism. London àti New York: Routledge.

Iggers, G. G. (1995). "Historicism: The History of the Term," Journal of the History of Ideas, vol. 56, no. 1, o.i. 129-152.

Ifamoṣe, F. O. (2004). "Twientieth Century Inter-Group Relations in Yorùbáland: A Retrospective and Perspective Analysis," Nsukka Journal of Humanities, no. 14, o.i. 95-108.

Johnson, O. S. (1921). The History of the Yorùbá: from the Earliest Time to the Beginning of the British Protectorate. London: Routledge and Kegan.

Kíaríbẹ̀ẹ́, L. A. (2021). “Ewì Gẹ́gẹ́ Bí Ètè Ogun Jíjà Láwùjọ Yorùbá”, Yorùbá Studies Review, Falola Toyin, Akintunde Akinyemi àti Adejumo Arinpe (Eds), vol. 6., no. 1., o.i. 73-90.

Ọdẹ́bọ̀dé, I. (2010). "Naming System During Yorùbá Wars: A Sociolinguistics Study," Names, vol. 58, no. 4, o.i. 209-218.

Ògúnníran, L. (2000). Ìbàdàn Mèsìọ̀gọ̀: Kìnnìún Ilẹ̀ Yorùbá (1829-1893). Ìbàdàn: Vantage Publishers.

Ológùró, S. (2020). "Balógun Ìbíkùnlé: A Warrior Hero of Ìbàdàn," Ìbàdàn: A Historical Culture and Socio-economic Study of an African City, Ògúnrẹ̀mí, G.O. (olóòtú), o.i. 434-447.

Oyèbíyí, O. (2008). 1810-2007 The Traditional Rulers of a Great City-Ìbàdànland & Notabe Events. Ìbàdàdàn: Boom Art/Printing Co.Ibadan.

Petraki, Z. (2021). "Hero-cult in Plato’s Phaedo, Republic and the Law," Synthesis, vol. 28, no. 2, e. 106.

Rappa, A. L. (2023). "The Concept of the Heroin Modernity," Bohr International Journal of Science and Humanities Research, vol. 2, no. 1, o.i. 131-133.

Reynolds, A. (1999). "What is Historicism," International Studies in the Philosophy of Science, vol. 13, no. 3., o.i. 275-287.

Stevanović, L. (2007). "Human or Superhuman: the Concept of Hero in Ancient Greek Religion and/in Politics," Bulletin of the Institute of Ethnography SASA LVI (2), o.i. 7-22.

Wei, X. àti Xu, J. (2012). "A Comparative Study on Heroism in Shooter and Water Margin," Theory and Practice in Language Study, vol. 2, no. 7, o.i. 1458-1464.

Publicado

27-08-2026

Cómo citar

KÍARÍBẸ̀Ẹ́ L. A. (2026). Ọ̀pẹ Ìjàyè ló le ròyìn ogun Ògúnmọ́lá": Ààrẹ Kúrunmí àti ìjìjàdù rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí akọni málegbàgbé: "A Palma da Vitória Pode Contar a História da 100ª Guerra": O Presidente Kurunmi e Sua Luta como Herói de Malegbage . NJINGA&SEPÉ: evista nternacional e ulturas, Línguas fricanas rasileiras, 6(Especial III), 42–55. ecuperado a partir de https://revistas.unilab.edu.br/njingaesape/article/view/2942