Ọ̀pálábà àti Oríògbadé Gẹ́gẹ́ bí Àkọni Òlówe Yorùbá

Opalaba e Oriogbade como heróis literários iorubás

Autores/as

Palabras clave:

Òwè Ọ̀pálábà, Òwe Oríògbadé, Òṣùwọ̀n Ìṣẹ̀dá, Òtítọ́ Ìjìnlẹ̀-Ọ̀rọ̀

Resumen

"Òwe ni ẹṣin ọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀ ni ẹṣin òwe, bọ́rọ̀ bá sọnù, òwe ni a fi ń wá a." Àwọn Yorùbá máa ń júbà àgbà ṣíwájú kí wọ́n tó pa òwe láti fi hàn pé ọ̀rọ̀ àgbà ni ó jẹ́ . Èyí ni ó fa ìpèdè "àwọn àgbà bọ́, wọ́n ní..." tí wọ́n máa ń sọ ṣíwájú kí wọ́n tó pa òwe. Lára àwọn ẹ̀dá-ìtàn àlohùn tí Yorùbá máa ń so mọ́ òwe ni Ọ̀pálábà. Nítorí pé àwọn òwe Ọ̀pálábà jẹ́ òtítọ́ ọ̀rọ̀ ajẹmẹ́fẹ̀ ni a ṣe yàn láti fi òwe rẹ̀ wé àwọn òwe ajẹmẹ́fẹ̀ àgbélẹ̀rọ Kọ́lápọ̀ Ọdẹ́lẹ́yẹ Oríògbadé, tóun náa jẹ́ ọ̀jìnmì nínú òwe pípa ní ìlú Ìbàdàn lóde òní. A ṣe àṣàyàn òwe Ọ̀pálábà àti ti Oríògbadé fún ìtúpalẹ̀. A fi ọ̀rọ̀ wá àwọn àgbààgbà lẹ́nu wò nípa òwe Ọ̀pálábà, a sì ṣe àkásílẹ̀ àwọn òwe Oríògbadé láti inú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò tí àwọn ènìyàn ti ṣe fún un lórí ìtàkùn àgbáyé. Ìwọ̀nyí jẹ́ détà ìpìlẹ̀ fún iṣẹ́-ìwádìí yìí. Orí tíọ́rì ìmọ̀ ọnà-ìsọ̀tàn ni a gbé ìtúpalẹ̀ iṣẹ́ yìí lé. Ìwádìí yìí fi hàn pé òwe Ọ̀pálábà kò wọ́pọ̀ mọ́, àti pé òtítọ́ ọ̀rọ̀ àti àwàdà ni àbùdá pàtàkì tó pa òwe Ọ̀pálábà pẹ̀lú ti Oríògbadé pọ̀. Iṣẹ́ yìí tún fi hàn pé ìtàn tí òwe Ọ̀pálábà sáábà máa ń sọ ni àbùdá tó yà àwọn òwe rẹ̀ sọ́tọ̀. Ìwádìí náà tún jẹ́ ká mọ̀ pé òwe le kú tí a kò bá lò ó mọ́ àti pé ìṣẹ̀dá òwe titun lè wáyé nípa lílo òtítọ́ ìjìnlẹ̀-ọ̀rọ̀ àti àwàdà gẹ́gẹ́ bí òṣùwọ̀n ìṣẹ̀dá. 

********

"O provérbio é o cavalo da fala, a fala é o cavalo do provérbio; se um provérbio se perde, usa-se um provérbio para encontrá-lo." O povo iorubá faz uma reverência a um ancião antes de proferir um provérbio, para demonstrar que se trata de um dito de ancião. Essa é a razão da expressão "os anciãos chegaram, eles dizem...", utilizada antes de se contar um provérbio. Entre as figuras históricas que o povo iorubá associa aos provérbios está Opalaba. Visto que os provérbios de Opalaba são provérbios autênticos, optamos por compará-los aos provérbios do famoso autor de provérbios Kolapo Odeleye Oriogbade, um mestre na arte dos provérbios em Ibadan nos dias de hoje. Selecionamos os provérbios de Opalaba e de Oriogbade para análise. Entrevistamos anciãos sobre os provérbios de Opalaba e compilamos uma lista de provérbios de Oriogbade a partir de entrevistas com pessoas de várias partes do mundo. Esses constituem os dados básicos desta pesquisa. A análise deste trabalho fundamenta-se na teoria da retórica. A pesquisa demonstra que os provérbios de Opalaba não são comuns e que a veracidade e o humor são as principais características que os distinguem dos provérbios de Oriogbade. O trabalho também revela que a narrativa frequentemente contada pelos provérbios de Opalaba é o traço que os diferencia. O estudo mostra ainda que os provérbios podem cair em desuso e desaparecer, e que a criação de novos provérbios pode ocorrer tendo a verdade e o humor como critérios de criação.

Descargas

Los datos de descargas todavía no están disponibles.

Biografía del autor/a

Luqman Abísọ́lá KÍARÍBẸ̀Ẹ́, Osun State University, Osogbo, Nigeria

Lectures at the Linguistics and Nigerian Languages department, Faculty of Culture, College of Humanities and Culture, Ọ̀ṣun State University, Nigeria. He specialized in Yorùbá oral poetry and focused his research on African oral performatives and sustainable development. Kíaríbẹ̀ẹ́ has publications in reputable journals across the global world.

Citas

Adegboyega, O. O. (2017). "Philosophical Issues in Yorùbá Proverbs," International Journal of African Society, Cultures and Traditions, 5 (2), o.i. 21-30.

Ademowo, A. J. àti Balogun, N .O. (2014). "Proverbs, Values and the Development Question in Contemporary Africa: A Case Study of Yorùbá Proverbs," Antropologija, 14(2), o.i. 149- 161.

Aford, K. [@kilontrendingblog]. (2025, September 19). Battel fire Oriogbade’s Wisdom Na fire. #YorubaNationNow#trendingvideo#viralpage#viralreelsfb[video]. TikTok. https://www.tiktok.com/kilontrendingblog/video

Akinlotan, O. (2022). "Popular Ibadan Vulcaniser, Oriogbade’s Daughters Returns to School," Premium Times, https://www.premiumtimesng.com/entertainment/naija-fashion/555252-popular-ibadan-vulcaniser-oriogbades-daughter-returns-to-school.html

Aláwodé, K. [@yorubadunolinetv007]. (2025, July 25). Oriogbade. #ibadan#oriogbade#oriyomihamzat#trinity_tnt#viraltiktok[video]. TikTok. https://www.tiktok.com/yorunaonlinetv007/video

Balógun, L. (2018). "Poetics of Mnemonic Strategy: Adaptation and Spiritual of Being & Thing in Túndé Kèlání Ṣaworoidẹ and The Narrow Path," Journal of African Films and Diapora Studies, 1(1), pp. 53-74.

Ejolabi, C. [@funnyejolabicomedy]. (2025, November 25). Oriogbade don’t kill me now. [video]. TikTok. https://www.tiktok.com/funnyejolabi.comedy/video

FelaGamo, [@FelaGamo40]. (2025, November 27). #felagamo#fyp#viralvideos [video]. TikTok. https://www.tiktok.com/felagamo40/video

Fludernik, M. (2009). An Introduction to Narratology. London: Routledge.

HannySur, [@hannysur]. (2026, January 25). Kolapo Oriogbade. http://www.tiktok.com/hannysur

Johnson, O. S. (1921). The History of the Yorùbá: from the Earliest Time to the Beginning of the British Protectorate. London: Routledge and Kegan.

Kèlání, T. (1999). Ṣaworiidẹ. Lagos: Mainframe Production.

Kèlání, T. (2002). Agogo Èèwọ̀. Lagos: Mainframe Production.

Ògúndèjì, P. A. (1991). Introduction to Yorùbá Oral Literature. Ibadan: University of Ibadan Centre for External Studies.

Ọládàpọ̀, Ọ. (1973). Àròyé Akéwì: Apá Kìn-ín-ní. Ìbàdàn: Oníbọnòjé Press & Book Industries (NIG) LTD.

Olanrewaju, F. T. (2020). "Yorùbá Proverbs as Expression of Socio- Cultural Identity in the South-Western, Nigeria," International Journal of Language and Linguistics, 7(3), o.i. 69-77.

Ọlátúnjí, O. Ọ. (1984). Features of Yorùbá Oral Poetry. Ibadan: University Press PLC.

Owómóyèlá, O. (2005). Yorùbá Proverbs. Lincoln and London: University of Nebraska Press.

Panggabean, D. S. (2020). "The Basic Concept of Narratology and Narrative," Language Circle: Journal of Language and Literature, 14(2), o.i. 185-190.

Punch Newspapers (2022). "Meet ‘Oriogbade’ Ibadan Man Popular for Witty Yoruba Proverbs," Punch Nigeria Limited, https://punch.ng.com/meet-oriogbade-ibadan-man-popular-for-witty-yoruba-proverbs

Rashy Babs. [@rashybabs]. (2024, April 7). Kolapo is a vulcaniser popular on social media for his brilliant use of Yoruba proverbs. #ibadan#oyostate#Yoruba#tinubu#rashybabs#oriogbade[video]. https://www.tiktok.com/rashybabs/video

Publicado

27-08-2026

Cómo citar

KÍARÍBẸ̀Ẹ́ L. A. (2026). Ọ̀pálábà àti Oríògbadé Gẹ́gẹ́ bí Àkọni Òlówe Yorùbá: Opalaba e Oriogbade como heróis literários iorubás. NJINGA&SEPÉ: evista nternacional e ulturas, Línguas fricanas rasileiras, 6(Especial II), 65–78. ecuperado a partir de https://revistas.unilab.edu.br/njingaesape/article/view/2905