Títayọ Gbèdéke Àṣà: Àgbéyẹ̀wọ̀ Obìnrin nínú Eré-oníṣe Ajẹmọ́tàn Fúnmiláyọ̀ Ransome Kútì àti Ẹfúnróyè Tinubu
Excelência Cultural: O Respeito às Mulheres no Drama de Funmilayo Ransome-Kuti e Efunroye Tinubu
Keywords:
Àṣà, Ẹfúnróyè Tinubu, Funmilayo Ransome-Kuti, Ìṣègbèfábo, ObìnrinAbstract
Àṣà Yorùbá láyé àtijọ́ fi àwọn obìnrin sí ọwọ́ ẹ̀yìn nínú dídi ipò adarí tàbí ipò òṣẹ̀lú mú, pàápàá jùlọ níbi tí a bá ti rí àwọn ọkùnrin. Ipò àti ojúṣe àwọn obìnrin láwùjọ Yorùbá sábà máa ń dá lórí ipa wọn nínú ilé gẹ́gẹ́ bí olùtọ́jú ilé, ọmọ àti ọkọ. Èyí wà ní ìbámu pẹ̀lú àrògún àti àròjinlẹ̀ ẹ̀yà yìí bí ó ṣe hàn nínú òwe, àṣamọ̀ àti ìṣe wọn lórísiríṣi. Nípa báyìí, àwọn obìnrin Yorùbá kì í bìkítà láti yọjú sípò adarí tàbí láti fẹ́ kópa ìṣèlú nínú àwùjọ wọn. Àmọ́ ṣá, nínú ìtàn àwùjọ náà àwọn obìnrin méjì kan wà tí wọ́n kọ̀ láti jẹ́ kí àṣà Yorùbá rìn wọ́n mọ́lẹ̀. Wọ́n kópa tó lápẹrẹ nínú ìṣẹ̀lú, bẹ́ẹ̀ sì ni wọ́n lẹ́nu ọ̀rọ̀ níbi tí àwọn ọkùnrin náà bá ri ń sọ̀rọ̀. Àwọn obìnrin méjì yìí ni; Funmilayo Ransome-Kuti àti Ẹfúnróyè Tinubu. Iṣẹ́ ìwádìí yìí tọpinpin ojúṣe àwọn obìnrin láwùjọ gẹ́gẹ́ bí ó ṣe hàn nínú fíìmù Funmilayo Ransome-Kuti àti eré-onítàn àpilẹ̀kọ Ẹfúnróyè Tinubu, tí a fi sọ ìtàn ìgbésí ayé àwọn akọnibìrin méjéèjì yìí. Ó ṣe àfihàn ipa ríbiribi tí wọ́n kó nínú ìlọsíwájú àwùjọ, bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó tayọ gbèdéke ohun tí a mọ obìnrin mọ̀ láwùjọ Yorùbá. Iṣẹ́ yìí ṣàmúlò ìtúpalẹ̀ ajẹmo-fíìmù gẹ́gẹ́ bí ọgbọ́n ìwádìí, tíọ́rì ìṣègbèfábo la lò láti ṣòdiwọ̀n fún àtúpalẹ̀. Àbájáde ìwádìí fi hàn pé àwọn obìnrin lè kópa pàtàkì láwùjọ yàtọ̀ sí ojúṣe wọn nínú ẹbí. Ìwádìí yìí tún tọ́ka sí i pé àwọn obìnrin máa ń kojú àwọn ìṣòro lóríṣìíríṣìí látara pé wọ́n ń ṣakitiyan láti ṣe àwọn ojúṣe wọ̀nyìí láwùjọ. Ọ̀kan lára rẹ̀ ni àtakò tí ó lè fẹ́ wáyé láti ọ̀dọ̀ àwọn ọkùnrin, owó àti ààbò jẹ́ àwọn ìṣòro mìíràn tí wọ́n máa ń kojú. Iṣẹ́ yìí dábàá pé kí àwùjọ rí àwọn obìnrin gẹ́gẹ́ bí alátìlẹyìn àti olùrànlọ́wọ́ fún àwọn okùnrin, tí wọ́n wúlò ní ipò òṣèlú, tí wọ́n sì lè ṣe takuntakun.
******
Historicamente, a cultura iorubá marginalizou as mulheres, impedindo-as de ocupar cargos de liderança ou políticos, especialmente em contextos onde homens estavam presentes. O status e as responsabilidades das mulheres na sociedade iorubá baseiam-se frequentemente em seus papéis domésticos como cuidadoras do lar, dos filhos e do marido. Isso está em consonância com as crenças e a ideologia desse povo, refletidas em seus diversos provérbios, ditados e práticas. Consequentemente, as mulheres iorubás, em geral, não buscam emergir como líderes nem participar da política em sua sociedade. No entanto, a história dessa sociedade registra duas mulheres que se recusaram a se deixar limitar pela cultura iorubá. Elas tiveram uma participação política de destaque e chegaram a se manifestar mesmo quando homens estavam falando. Essas duas mulheres são Funmilayo Ransome-Kuti e Efunróyè Tinubu. Este projeto de pesquisa explora o papel da mulher na sociedade, conforme retratado no filme *Funmilayo Ransome-Kuti* e no documentário *Efunróyè Tinubu*, obras que narram a trajetória dessas duas heroínas. O estudo destaca a contribuição significativa que elas deram ao progresso da sociedade, indo além do que é convencionalmente conhecido sobre o papel da mulher na cultura iorubá. A pesquisa utiliza a análise fílmica como método, tendo a teoria de gênero como referencial teórico. Os resultados indicam que as mulheres podem desempenhar papéis importantes na sociedade, para além de suas funções familiares. O estudo também aponta os diversos desafios que as mulheres enfrentam ao tentar cumprir esses papéis sociais; entre eles, destaca-se a possível oposição masculina, bem como questões relacionadas a recursos financeiros e segurança. Por fim, o trabalho sugere que a sociedade deve reconhecer as mulheres como apoiadoras e colaboradoras dos homens, capazes de atuar com eficácia em cargos políticos e de realizar grandes feitos.
Downloads
References
Abímbólá, W. (1992). Àwọn ojú odù mẹ́rẹ̀ẹ̀rindínlógún. Oxford University Press.
Adeoye, C. L. (1979). Àṣà àti ìṣe Yorùbá. Oxford University Press.
Adesanya, A., Lawal, O., & Johnson, S. (2025). An Examination of Indigenous Media Use and Promotion in Lagos State-Owned Broadcasting Stations’ Programmes. LASU Postgraduate School Journal, 1(2), 93-107.
Adeyemi, L. (2019). Tíòrì lítíréṣọ̀ ní èdè Yorùbá. Shebiotimo Publications.
Aina, O. I. (2012). Two halves make a whole: Gender at the crossroads of the Nigerian development agenda. Gender and Development, 20(3), 439–454.
Aina, O. I. (2013). Women, culture and society in Nigeria. Spectrum Books.
Amadiume, I. (1997). Re-inventing Africa: Matriarchy, religion and culture. Zed Books.
Awosusi, O. A. (2025). Anatomical research of Yoruba women’s political contributions during the colonial period. African Journal of Culture, History, Religion and Traditions, 8(2), 1–10.
Balogun, O. A. (2010). Proverbial oppression of women in Yoruba African culture: A philosophical overview. Thought and Practice: A Journal of the Philosophical Association of Kenya.
Barber, B. R. (1984). Strong democracy: Participatory politics for a new age. University of California Press.
Bolanle, A. P. (2024). Fúnmiláyọ̀ Ransome-Kútì. BAP Productions.
Butler, J. (1990). Gender trouble: Feminism and the subversion of identity. Routledge.
Chukwuma, H. (1994). Feminism in African literature: Essays on criticism. New Generation Books.
Ehibor, O. J., Osiyemi, R. A., Eyisi, J., Jr., et al. (2025). Illocutionary and perlocutionary leadership acts in Bolanle Austen-Peters’ Funmilayo Ransome-Kuti. Forum for Linguistic Studies, 7(12), 950–959. https://doi.org/10.30564/fls.v7i12.919
Gilligan, C. (1982). In a different voice: Psychological theory and women’s development. Harvard University Press.
Hudson-Weems, C. (1993). Africana womanism: Reclaiming ourselves. Bedford Publishers.
Ìṣọ̀lá, A. (1989). Ẹfúnróyè Tínúbú. Oníbọnòjé Press.
Kabeer, N., & Natali, L. (2013). Gender equality and economic growth: Is there a win-win? (IDS Working Paper No. 417). Institute of Development Studies.
Kolawole, M. E. (1997). Womanism and African consciousness. Africa World Press.
Mama, A. (2001). Beyond the masks: Race, gender and subjectivity. Routledge.
Odebode, I. (2015). Women in Nigerian politics: Challenges and prospects. International Journal of Gender and Development Issues, 14(2), 33–48.
Ogini, E. (1996). Feminism and womanism: A historical perspective. In A. Adebayo (Ed.), Feminism and Black women’s creative writing: Theory, practice, criticism (pp. 11–20). AMD Publishers.
Ogundipe, M., Adepoju, A., & Kolawole, M. (2016). The economic contributions of women to sustainable development in Nigeria. African Journal of Development Studies, 8(1), 101–119.
Olaogun, S., & Adeleke, L. A. (2022). A pragmatic analysis of questions in Ẹ̀fúnróyè Tínúbú. Language Review: International Journal of Linguistics, 1(1).
Olaleye, S. K., Gbadamosi, O. A., & Adekoya, J. S. (2024). The role of women in political activism in pre- and post-colonial Yoruba history: Lessons for contemporary society. Journal of African History, Archaeology and Tourism, 2(2), 99–118.
Òjó, E. T. (2024). Representation of women in African proverbs: The Yorùbá example. In A. Bolarinwa, M. Akinseli, & A. Oyebamiji (Eds.), New trends in Yoruba studies: Essays in honour of Arinpe Adejumo (pp. 230–250). Matrix Publication.
Okeke-Ihejirika, P. E. (2004). Negotiating power and privilege: Igbo career women in contemporary Nigeria. Ohio University Press.
Oyèwùmí, O. (1997). The invention of women: Making an African sense of Western gender discourses. University of Minnesota Press.
Pateman, C. (1988). The sexual contract. Stanford University Press.
Rawls, J. (1971). A theory of justice. Belknap Press of Harvard University Press.
UN Women. (2019). Progress of the world’s women 2019–2020: Families in a changing world. United Nations Entity for Gender Equality and the Empowerment of Women.
Downloads
Published
How to Cite
Issue
Section
License
Copyright (c) 2026 NJINGA&SEPÉ: Revista Internacional de Culturas, Línguas Africanas e Brasileiras

This work is licensed under a Creative Commons Attribution-NonCommercial-NoDerivatives 4.0 International License.
Authors who publish in this journal agree to the following terms:
Authors maintain copyright and grant the journal the right to first publication, the work being simultaneously licensed under the Creative Commons Attribution License, which allows the sharing of the work with recognition of the authorship of the work and initial publication in this magazine.
Authors are authorized to assume additional contracts separately, for non-exclusive distribution of the version of the work published in this journal (eg, publishing in institutional repository or as a book chapter), with acknowledgment of authorship and initial publication in this journal.
Authors are permitted and encouraged to publish and distribute their work online (eg in institutional repositories or on their personal page) at any point before or during the editorial process, as this can generate productive changes, as well as increase impact and citation of the published work (See The Effect of Open Access).