Àwọn Akíkanjú Ẹ̀yà Yorùbá Gẹ́gẹ́ Bí Àwòta Fún Ìwà Akíkanjú Àwọn Adúláwọ̀

Heróis iorubás como espelho do comportamento heroico do povo negro

Autores

  • O̩mo̩layo̩ Durotade OGUNLO̩LA University of Ilo̩rin – Nigeria

Palavras-chave:

Akíkanjú, Ẹ̀yà Yorùbá, Àwòta Ìwà, Adúláwọ̀

Resumo

Kí a tó lè pe ẹnìkan ní Akíkanjú ènìyàn, yálà ọkùnrin tàbí obìnrin, ní àdúgbò rẹ̀ tàbí níbòmíràn, ẹni bẹ́ẹ̀ gbọ́dọ̀ ti ṣe ohun ribiribi pàápàá jùlọ, èyí tó ṣe àwùjọ rẹ̀ ní àǹfààní. Káàkiri àgbáyé ni a ti rí àwọn Akíkanjú ènìyàn bẹ́ẹ̀ kódà ní ilẹ̀ Adúláwọ̀ pàápàá. Àpilẹ̀kọ yìí jíròrò lórí ipa adarí àwọn akíkanjú Ilẹ̀ Adúláwọ̀ lọ́kùnrin àti lóbìnrin a sì fi àwọn Yorùbá ní ìhà Gúsù ilẹ̀ Nàìjíríà ṣe òdiwọn. Ìtàn ìwáṣẹ̀ fi yé wa pé ìran Yorùbá ti ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn pàtàkì látẹ̀yìnwá lọ́kùnrin àti lóbìnrin tí wọ́n ti ṣe ohun mánígbàgbé láàrin ènìyàn wọn. Ìwádíí yìí ṣe àgbéyẹ̀wò ohun tí wọn ṣe àti ipa wọn lorí àwùjọ olukúlùkù wọn lápapọ̀. Iṣẹ́ ìwádìí yìí mú wá sí ìrántí akitiyan àti àṣeyọrí àwọn ọmọ Yorùbá tí a lè pè ní akíkanjú ènìyàn lọ́kùnrin àti lóbìnrin, èyí tí a gbàgbọ́ pé kò yẹ kí ó parun. Lára èròǹgbà iṣẹ́ iwádìí yìí ni: (a). Láti ṣe kóríyá fún àwọn ọ̀dọ́ ìwòyí láti rìn ní ọ̀nà tí àwọn ènìyàn wọ̀nyìí rìn. (b). Láti mú kí ẹ̀mí ìdáraẹnilójú, ìfaraẹnijì fún ìmúdúró àti ìtẹ̀síwájú àwùjọ ẹni gbèrú sí i lọ́kàn wọn. Àpilẹ̀kọ yìí ṣe àyẹ̀wò àwọn akíkanjú ilẹ̀ Yorùbá márùn-ún, ọkùnrin márùn ún àti obìrin márùn ún.  sàfiwé ipa wọn, bákan náà ni a sọ èrò tiwa nípa wọn. Àpilẹ̀kọ yìí ṣe àmúlò Tíọ́rì ìtúpalẹ̀ tó jẹ mọ́ èrò àti ìhùwàsí ẹ̀dá ènìyàn, èyí tí àpapọ̀ Ivan Pavlov, Skinner, B.f àti John Watson se agbátẹrù rẹ̀.

******** 

Para ser chamado de herói — seja homem ou mulher, em sua comunidade ou em qualquer outro lugar —, o indivíduo deve ter realizado algo grandioso, especialmente algo que tenha beneficiado sua comunidade. Pessoas heroicas são encontradas em todo o mundo, inclusive no mundo negro. Este artigo aborda o papel dos heróis do mundo negro, tanto homens quanto mulheres, tomando como referência o povo iorubá, do sul da Nigéria. A história nos mostra que o povo iorubá teve muitos homens e mulheres notáveis ​​que realizaram feitos inesquecíveis em meio ao seu povo. Este estudo examina as ações dessas pessoas e o impacto que tiveram em suas comunidades como um todo. O projeto de pesquisa resgata os esforços e as conquistas de iorubás que podem ser considerados heróis e heroínas — figuras que, a nosso ver, não devem ser esquecidas. Entre os objetivos deste projeto de pesquisa, destacam-se: (a) Inspirar a juventude atual a seguir os passos dessas pessoas; (b) Incutir neles um espírito de autossuficiência e um compromisso com a manutenção e o progresso da sociedade. O artigo analisa cinco heróis iorubás — cinco homens e cinco mulheres —, comparando suas trajetórias e apresentando nossas próprias opiniões a respeito deles. O trabalho fundamenta-se na teoria de análise do pensamento e do comportamento humano pioneiramente desenvolvida por Ivan Pavlov, B.F. Skinner e John Watson.

Downloads

Não há dados estatísticos.

Biografia do Autor

O̩mo̩layo̩ Durotade OGUNLO̩LA , University of Ilo̩rin – Nigeria

is a Ph.D holder in Yorùbá Literature from the Department of Linguistics and Nigerian Languages, University of Ilo̩rin. He specializes in Yorùbá Literature and culture. He has done extensive research on Yorùbá Literature and Cultural values. He has also written quite a number of Yorùbá texts (novels and plays) and at least thirty-five (35) jornal articles. He is currently an Associate Professor.

Referências

Àánúolúwapọ̀ (2003). “Women in the Yorùbá Religious Sphere”. In McGill: Studies in History of Religion. Suny Press.

Accord Concordial, (2017). “The continuous search for Nigeria’s elusive Unity” Retrieved 11-11-2025.

Adams Lawal Babatunde (2002). “The History, People and Culture of Ìta Tinúbú Community”. Lagos. Tinubú Foundation.

Bíọdún Ṣolá (2018). “Mọremi Ajasórò: The Woman who used her beauty to save her people where men failed. Legiting – Nigeria News. Retrived 11-11-2025.

Delano̩, I.O. (1955). Aiye D’aiye Oyinbo. London: T. Nelson and sons, Limited.

Fasinro, Hasan Adisa Babatunde (2004). “Political and Cultural Perspectives of Lagos. University of Michigan.

Hannam, Jane, Auditerlonie, Mitzi, Holden, Katherine (eds) (2000). “Ransome-Kuti Funmilayọ”. In International Encyclopedia of Women Sufferage. Santa Barbara, California.

Isola, A. (1970). Efúnsetán Aníwúrà. Ìbàdàn: University Press.

Ìsola, A. (1983). Olú Ọmọ. Ìbàdàn: Oníbonòjé Press and Book Industries Nigeria Limited.

Johnson-Odim, Cheril (1978).” Nigerian women and British Colonialism: The Yorùbá Example with Selected Biographies (Ph.D). Northwestern University.

Johnson-Odim, Cheril (1992). “On behalf of Women and the Nation: Funmi Ransome Kuti and the Struggle for Nigeria Independence”. In Johnson-Odim, Cheril, Strobel, M. (eds). Expanding the boundaries of Women’s history: Essays on women in the third World”. Indiana University Press. Pp.144-157.

Johnson-Odim, Cheril, Mba & Nina Emma (1997). ” For Women and the Nation: Funmilayọ Ransome-Kuti of Nigeria”. University of Illinois Press.

Kọlawọle, M.E. (1997). “Womanism and African Consciousness”. Africa World Press.

Mayer, Adan (2016). “Olufunmilayọ Ransome Kuti” Naija Marxisms Revolutioning Thought in Nigeria. Pluto Press. Pp. 172-176.

New Encyclopedia of Africa (2008). John Middletoner & Joseph C. Miller (eds). “Tinubu Madame”. Detroit: Charles Scribner’s Sons. Vol 5.

Ogunl̩o̩la, O.D. (2011): Womanhood in the Bible and in Yorùbá Tradition: Towards the Elevation of Women in the Nigerian Society. In Ìlọrin Journal of Linguistics, Literature and Culture. 2. 103-126. Published by Department of Linguistics and Nigerian Languages, University of Ilorin.

Ọláìyá, Táíwò Àkàndé (2016). Proto-Nationalism as Sub-Text for the crisis of Governance in Nigeria. In Sage Open.

Research Foundation (2016). “Awolọwọ, Chief Ọbafẹmi Jeremiah: Biographical Legacy.(Retrieved 11-11-2025).

Sherwood Marika (1995). Manchester and the 1945 Pan African Congress”. London.Savanah Press.

Tribune On-line (27-09-2021). “Remembering Moremi Ajasórò”

Yemitàn, Ọládipọ̀ (1987). “Madame Tinubu: Merchant and King Maker: Ìbàdàn. University Press.

Downloads

Publicado

27-08-2026

Como Citar

OGUNLO̩LA O. D. (2026). Àwọn Akíkanjú Ẹ̀yà Yorùbá Gẹ́gẹ́ Bí Àwòta Fún Ìwà Akíkanjú Àwọn Adúláwọ̀: Heróis iorubás como espelho do comportamento heroico do povo negro. JINGA SEPÉ: evista nternacional e ulturas, Línguas fricanas rasileiras (ISSN: 2764-1244), 6(Especial II), 128–140. ecuperado de https://revistas.unilab.edu.br/njingaesape/article/view/2909