Àyìnlá ọmọwúrà gẹ́gẹ́ bí akọni ọ̀kọrin àpàlà yorùbá

A águia-real como heroína da canção folclórica iorubá

Autores

Palavras-chave:

Àyìnlá Ọmọwúrà, Ako̩Ni, Adúláwọ̀, Àṣà, Lítíréṣọ̀, Orin

Resumo

Ìwádìí ti fì ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé tí a bá fẹ́ mọ ̀nípa litiréṣọ̀ ati àṣà àwọn ẹ̀yà ènìyàn kan, a le tọpa rẹ̀ dé inú àwọn orin ìbílẹ̀ wọn. Orin Ayinla Ọmọwura ni bébà yii gbéyẹ̀wò pẹ̀lú èrò láti ṣe àgbékalẹ̀ àti àlàyé àwọn orin rẹ̀ bí wọ́n ṣe ń ṣe ìgbélárugẹ àwọn àṣà Yorùbá tó níyelórí. Tíọ́rì ìfojú ìmò̩ ìbára-e̩ni-gbépọ̀ láwùjọ tó gbàgbó̩ pé ìgbé-ayé è̩dá nínú àwùjo̩, ìgbàgbó̩ rè̩, às̩à rè̩ àti èdè rè̩ jé̩ òpómúléró fún ìdúró è̩dá láyé ni a fi ṣe ìtúpalè̩ mẹ́rin nínú àwo̩n orin Ayinla Ọmọwura tí ó ń sò̩rò̩ nípa às̩à Yorùbá. Awo̩n orin rè̩ náà nì: National Census (Vol.5), Olóògbé Muritala Muhammad (Vol.9), Omi Tuntun (Vol.17), àti Àwa kì í ṣe Olódì Wọn (V0l. 19).  Ìwádìí fi hàn pé orin Ayinla Ọmọwura ń ṣe àfihàn ìranYorùbá gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà kan pàtàkì nílẹ̀ Adúláwò pẹ̀lú ìpolongo àwọn àṣà àti ìṣe Yorùbá bí ọ̀rọ̀ lọ́kọláya àti ìtọ́jú ẹbí, ìwà rere, àti ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láwùjọ. Bákan náà, Ayinla Ọmọwura tún máa ń lo èdè lọ́nà àrà àti òwe lóríṣiríṣi ninu orin rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí agbédègbẹ́yọ̀. Àbájáde is̩é̩ ìwádìí yii fi Ayinla Ọmọwura hàn gé̩gé̩ bí akọni olórin tí ó ń fi orin rẹ̀ dá àwùjọ lẹ́kọ̀ọ́, s̩e ì̀ròyìn ohun tó ń lọ láwùjọ àti pé amúlùúdùn ni. Láìse àníàní, Àyìnlá Ọmọwura fi orin rẹ̀ ṣègbè fún ìlọsíwájú àti ìdàgbàsókè èdè, àṣà àti lítíréṣọ̀ Yorùbá pẹ̀lú ẹ̀ri ́pé àwọn ènìyàn sì máa ń tọ́kasí orin rẹ̀ láti fi ṣẹ̀rí tàbí yanjú ọ̀rọ̀ kan tàbí òmíràn nígbà ayé rẹ̀ àti lẹ́yìn ìpapòdà rẹ̀.

******* 

Pesquisas comprovam que, para conhecer a literatura e a cultura de um povo, podemos recorrer às suas canções tradicionais. Este artigo examina as canções de Ayinla Omowura com o objetivo de apresentá-las e explicá-las, visto que promovem valiosas tradições iorubás. A teoria da interação social — segundo a qual a vida da natureza na sociedade, bem como sua cultura e linguagem, constituem os fundamentos para a sobrevivência dessa natureza no mundo — é utilizada para analisar quatro canções de Ayinla Omowura que abordam a cultura iorubá. Entre suas canções, destacam-se: *National Census* (Vol. 5), *Olóògbé Muritala Muhammad* (Vol. 9), *Omi Tuntun* (Vol. 17) e *Àwa kií se Olódì Won* (Vol. 19). Os estudos demonstram que as canções de Ayinla Omowura refletem a identidade iorubá como um importante grupo étnico da região de Aduláwó, ao mesmo tempo em que promovem costumes e práticas iorubás, como o casamento, o cuidado com a família, a moralidade e a cooperação social. Além disso, na qualidade de figura folclórica, Ayinla Omowura emprega a linguagem de diversas formas e utiliza provérbios em suas músicas. Os resultados desta pesquisa revelam Ayinla Omowura como uma cantora heroica que utilizava sua música para educar e informar o público sobre os acontecimentos sociais, bem como para entreter. Sem dúvida, Ayinla Omowura contribuiu para o progresso e o desenvolvimento da língua, da cultura e da literatura iorubás por meio de sua música; há evidências de que as pessoas frequentemente recorrem a suas canções para comprovar fatos ou solucionar questões, tanto durante sua vida quanto após sua morte.

Downloads

Não há dados estatísticos.

Biografia do Autor

Akeem Kolawole OYEBAMIJI , Federal University of Education -Nigeria

is an Associate Professor at the Federal University of Education, Zaria. He attended Obafemi Awolowo University, Ile-Ife and obtained B.A Education (Honours) degree in Yoruba Education. Masters of Arts and Doctor of Philosophy in Yoruba Literature, University of Ibadan. He specializes in Literature, Children/pupils Pedagogy and the environment. He is a versatile poet. He has presented well-researched articles in conferences and published papers in both local and international journals of repute. He also belongs to many professional associations including E̩gbé̩ Akó̩mo̩lédè àti às̩à Yorùbá and Yoruba Studies Association of Nigeria (YSAN).

Abidemi Olusọla BO̩LARINWA , University of Ibadan, Nigeria

is an Associate Professor in the Department of Linguistics and African Languages, University of Ibadan, Nigeria. Abidemi has broadened her long-life interests in Literature with an M.A and Ph.D degrees in Yoruba Literature from the University of Ibadan, Nigeria. Her current research interests include culture, film, conflict and gender studies. She is a member of several learned and professional associations, such as, International Society for Oral Literature in Africa (ISOLA), African Literature Association (ALA) and Yoruba Studies Association of Nigeria (YSAN). Presently, she is the Administrative Secretary of International Society for Oral Literature in Africa (ISOLA) and the Treasurer, Yoruba Studies Association of Nigeria (YSAN). She has numerous scholarly publications to her credit in local and international journals.

Referências

Adébò̩wálé, O. (2011).”Writing and Reacting: The experience in indigenous Yorùbá literary arts”. An inaugural lecture delivered at Adekunle Ajasin University, Àkùngbá, Àkókó, Nigeria

Agyekun, K. (2007). Introduction to Literature, Accra: Media design.

Ajíbàdé, G.O.(2012). The Yorùbá Oral Artists and Their Use of Words in A.G. Adejumọ (ed) Yoruba: Journal of Yoruba Studies Association of Nigeria, vol.7, no.1

Ajíbádé, G.O. (2008).”Representation of Gender Discourse in the Poetry of Akínwùmí Ìṣọ̀lá’ In Akínye̩mí, A. and Fálo̩lá, T. (eds) Emerging Perspectives on Akínwùmí Ìṣọ̀lá. Eritrea: African World Press Inc.

Bámidélé, I.O. (2003). Literature and Society. Ibadan: Stirling Horden Publishers, Nigeria Ltd.

Bó̩lárìnwá, A.O (2014). Forms and Content of Onímejò Festival Song. Journal of Nigerian Languages and Culture,. Vol 15, No. 1: 141-152 (Nigeria).

Bó̩lárìnwá, A. (2019).Ọnà ti Àrìnpé Adéjùmọ̀ Gbà Yí Ojú Àmúwáyé Obìnrin Padà Nínú Ewì Ròóore. Inquiry in African Languages and Literatures No 12. P. 76-86.

Bó̩lárìnwá, A.O. (2025). “Àfihàn Obìnrin Nínú Àwo̩n Àsàyàn Orin Àló̩ Onítàn Yorùbá” in Revista Njinga & Sepe: a journal of Culture and Literature in African Languages: Studies and Research. V. 5 n. Special 1.

Euba, A. (1975). The Interrelationship of Poetry and Music in Yorùbá Tradition ninu Abimbola, W. (ed) Yorùbá Oral Tradition: Selection from the Papers Presented at the Seminar on Yorùbá Oral Tradition, Poetry in Music, Dance and Drama

Fákáyọ̀dé, F. (2016). ”Ipa Tí Orin Ifá Ti Kó Nínú Ìrìnajò Ọgọ́rùn-ún Ọdún Orílẹ̀èdè Nàìjíríà”Nínú Fájẹ́nyọ̩̀ (ed) Ìtànsán Oòduà: Jọ́nà Ẹgbẹ́ Olùkọ́ Èdè Kọ́lẹ́ẹ̀jì Ẹ́ńsiì. Fọ́lúùmù 5, nọ́ḿbà 1.

Ìṣọ̀lá, A. (2010). “Making Culture Memorable. Essays on Language, Culture and Development”. Ibadan: DB Martoy Books Publication Ltd.

Ké̩hìndé, A. (2005). “Modern Novelists and Their Historical Sense: The Example of D.H. Lawrence and Virgina Woolf” In Ọlateju, M. and Oyeleye L.(eds). Perspectives on Language and Literature. Ilé-ifè̩: Ọbáfẹ́mi Awólọ́wò̩ University Press

Nanda, S. (1984). Cultural Anthropology. California: Wads Worth Publishing Company.

Ògúnpolú, T. (1975). “Preliminary Notes on Okosi Festival Songs” Ninu Abimbọla W. (ed) Yorùbá Oral Tradition: Selection from the Papers Presented at the Seminar on Yorùbá Oral Tradition, Poetry in Music, Dance and Drama.

Ògúnsìnà, B. (2006). Sociology of the Yorùbá Novels: An Introduction. Ìlo̩rin: Integrity Publication

Òjó E.T and Bọ́lárìnwá, A.O. (2021).”Tones and Stylistics of People’s Reception of Corona Virus in African Society: The Yorùbá Example”. Special Edition on Corona Virus by Yorùbá Journal of Yorùbá Studies Association of Nigeria. Vol. 10 No. 3 Pp 31-47.

Oyèbámijí, A.K and Bó̩lárìnwá A.O (2025) African Riddles and Their Pedagogical Value: The Yorùbá Example in IKR Journal of Education and Literature. Vol 1, No 1. Pp1-7.

Okoh, N. (2008). Preface to Oral Literature. Onitsha: African First Publishers.

O̩lájubù, O. (1981). Àkójọpọ̀ Iwì Egúngún, Ìkẹjà: Longman Nigeria Ltd.

O̩látúnjí, O. (1984). Feature of Yorùbá Oral Poetry. Ìbàdàn: University Press.

Olùkojú, E. (1994) The Study of Yorùbá Songs. Ibadan: Centre for External Studies, Faculty of Education, Univeristy of Ìbàdàn, Ìbàdàn.

Ọ̀pẹ́fèyítìmí, A. (2014) Tíọ́rì àti ìṣọwọ́lo-èdè. Ilé-Ifẹ̀: Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University Press.

Ọ̀pẹ́fèyítìmí, A. (2018) Women in Yoruba Culture: A Dozen of Academic Articles. Ìbàdàn: Penthouse Publications (Nig).

Oyèníyì, F. (2016) ”Àgbéyẹ̀wò Orin Nínú Orò Lékú” nínú Fajẹnyọ (ed) Ìtànsán Oòduà: Jọ́nà Ẹgbẹ́ Olùkọ́ Èdè Kọ́lẹ́ẹ̀jì Ẹ́ńsiì. Fọ́lúùmù 5, nọ́ḿbà 1

Surakat, T.Y. (2013). “Yorùbá-English code-switching in Àyìnlá Ọmọwúrà Àpàlà Music” in Ogunsiji, A, Kẹhinde, A. and Ọdẹbunmi, A. (Eds) Language, Literature and Discourse, A Festschrift in Honour of Prof. Lekan Oyeleye. Ibadan: Stirling-Horden Publishers Ltd.

Táìwò, A. (2013) “Ká rìn ká pọ̀: A Novelist Perspective on Security” In A.G. Adéjùmọ̀ (ed) Yorùbá: Journal of Yorùbá Studies Association of Nigeria. Vol.7, no. 2.

Downloads

Publicado

27-08-2026

Como Citar

OYEBAMIJI , A. K., & BO̩LARINWA A. O. (2026). Àyìnlá ọmọwúrà gẹ́gẹ́ bí akọni ọ̀kọrin àpàlà yorùbá: A águia-real como heroína da canção folclórica iorubá. JINGA SEPÉ: evista nternacional e ulturas, Línguas fricanas rasileiras (ISSN: 2764-1244), 6(Especial II), 111–127. ecuperado de https://revistas.unilab.edu.br/njingaesape/article/view/2908